Kádàrá ní ọ̀rọ̀ ẹ̀dá láyé, Mo gbà pé Ọlọrun ló kọ ikú ọkọ mi ni Saudi Arabia
Mo gba pé a dá mi sí láti tọ́jú àwọn ọmọ wa mẹta ti ọkọ mi fi sílẹ̀ lọ ni- Yetunde Morenikeji Raji
Abilekọ Yetunde Morenikeji Raji to jẹ aya oloogbe Ajani Raji ba BBC Yorùbá sọrọ lori iṣẹlẹ to gba ẹ̀mí ọkọ rẹ to tun sọ oun di aláàbọ̀ ara.
- Kílódé tí Ọọni Ife, Oba Ogunwusi kò fi gbọdọ̀ rí ọmọ rẹ̀ tuntun ti Olorì Naomi bí títí di bíi ẹ̀yìn oṣù mẹ́fà?
- Àwọn Olúkọ ìpínlẹ̀ Oyo fakọyọ lórí ètò Akọ́mọlédè àti Àṣà púpọ̀
- Kìí ṣe gbogbo èèyàn ló lè máa jẹ irú mi- Adebola, Iya Adigun onírú ìgbàlódé fárígá
- Toyin Abraham fi orin yẹ́ Iyabo Ojo sí níbi ìsìnkú ìyá rẹ̀, Falz di ẹni tí wọ́n fí òpópónà ṣọ orí rẹ̀
- Ọkùnrin tó fẹ́ fipábámilòpọ̀ fín ǹkan sí mi lójú nínú ọkọ̀, mó sá wọ igbó àmọ́...
- Kò sẹ́ni tó lè ní kí n má yan àwọn Baálẹ̀ nílùú Akure- Ọba Aladetoyinbo Aladelusi
O mẹnuba bi ọna iṣẹ naa ṣe ṣi silẹ fun ọkọ rẹ ni Saudi lẹyin to ṣiṣe pelu UCH àti fasiti LAUTECH
Yetunde Raji sọ nipa bi wọn ṣe kàgbákò ni ó ku ọ̀la ti oun a pada si orilẹ-ede Naijiria.



