Ọdún kan lẹ́yìn ogun Musulumi Rohingya, ìbànújẹ̀ dorí àgbà kodò
Ìgbé ayé àwọn aṣàtìpó Rohingya kò rọrùn rárá.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣàtìpó to sá kuro torí ogun Rohingya lo ṣì ń gbé nínú ìbànújẹ́ àti ẹ̀rù báyìí tó jẹ́ ọdún kan lẹyin iṣẹlẹ naa.
Ọmọ ọdun mẹẹdogun yii sọ ohun ti oju rẹ n ri pẹlu ẹ̀rù to n baa lori oyun to ni fun baba arúgbó to fẹ ẹ nibudo aṣatipo.