Oluwo: Oluwo ṣàlàyé ohun tó ń mú káwọn èèyàn máa gba tirẹ̀ láwùjọ

Oríṣun àwòrán, Instagram/oluwo of iwo land
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Oluwo ilu iwo, ọba Abdulrasheed Akanbi ti ṣalaye ohun to n mu ki tẹrutọmọ gba toun gẹgẹ bi kabiyesi.
Ninu ọrọ kan to fi sita loju opo Instagram rẹ, Oluwo jẹ ko di mimọ pe ifẹ ti awọn eeyan n ni si oun pẹlu ọwọ ti wọn n fun oun ko ṣa dede wa bikoṣe nipasẹ ohun ti oun n ṣe faraalu

Ba Akanbi ṣalaye pe bi eeyan ba ti n ṣe ohun to tọ lawujọ, o di didan karaalu o fẹran rẹ.
Skip Instagram post
Allow Instagram content?
Warning: Third party content may contain advertsThis article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post
- Báyìí ni àgbàọ̀jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù Diego Maradona ṣe wọ káà ilẹ̀ lọ lólú ìlú Argentina
- Ọmọbìnrin tó tayọ nínú ìdànwó WAEC ọdún 2019 pẹ̀lú A1 méje ti kú
- Wo ohun tí Ọọ̀ni, Sultan Sokoto sọ nípa ọta ìbọn tó gbẹ̀mí Ọba Olúfọ́n
- Àwọn Olúkọ ìpínlẹ̀ Oyo fakọyọ lórí ètò Akọ́mọlédè àti Àṣà púpọ̀
- Ọwọ́ Interpol àti ọlọ́pàá Nàìjíríà ti tẹ ọmọ Nàìjíríà mẹ́ta tó lu èèyàn 50,000 ní gbájúẹ̀










