Kie kie: Adeaga Bukunmi Ilori sọ bí Elẹ́dàá ṣe gbà fún un tó sọ ọ di eèyàn ńlá ní àwùjọ àwọn aláwàdà
Adeaga Bukunmi Ilori ni oruko apeja aderinpoṣonu lori Instagram ti ọpọ n pe ni Kie kie.
BBC Yoruba gba a lalejo nibi to ti raaye sọ ibẹrẹ igbesi aye rẹ ki Ori to gbe e de ibi to de bayii.
Kiekie salaye nipa ohun ti oju rẹ ri ko to deeeyan ati awọn ibi to ti kawe gboye.
- Mo rí ìpèníjà lórí eré oníjó láti ọ̀dọ̀ Krìsítẹ́nì aláṣọ funfun àti àwọn Mùsùlùmí - Alfa Sule
- Fífẹ̀ ju ìyàwó kan lọ ni àṣírí ẹ̀mí gígùn'
- Ṣé lóòtọ́- Bóo bá ń mu Garri jù tí wọ́n tàn ẹ́ pé ojú dídùn ni yóò gbẹ̀yìn rẹ; gbọ́ òótọ́ lẹ́nu onímọ̀
- Mi ò tí ì mọ obìnrin rí; kódà, mí ò ní 'Girlfriend'- Mr Macaroni
- Mọ̀ nípa ibùdó tí o ti le gba omi ọmú lọ́fẹ̀ẹ́ fún ọmọ ní Naijiria
- Ká ní pe àwa méjèèjì kò ní 'First Class' ni........- Taiwo Oluyori FUTA
- Njẹ́ ẹ mọ pẹ̀tẹ́ẹ̀sì àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà?
Adeaga Bukunmi ṣalaye bo ṣe lọ sí Bowen lọ ka iwe ati bi Coronavirus ṣe sọ o di ọmọ ologo.
Omo Ibadan yii sọ ohun ti lock down ṣe fun un to fi di gbajumọ alawada bayii.
Iwọ naa, dakun, ma ro ara rẹ pin, ọla a dara ti o ba le da ẹbun ti Oba Oke fun ọ mọ lasiko.





