Mr & Mrs Kogberegbe: Ṣé lọ́òtọ́ ọkọ àti ìyàwọ́ ní Mr & Mrs Kogberegbe? Àṣírí bí a ṣe ń ṣe ètò yìí rèé...
Arakunrin Olalekan ti ọpọ eniyan mọ si Mr Kogberegbe ninu eto Mr and Mrs Kogberegbe ti ni ọpọ igba ni eto ẹfẹ akọnilọgbọn nipa igbeyawo to ni itumọ naa ti sakoba fun oun.
Mr Kogberegbe sọ eyi lasiko ifọrọwerọ pẹlu BBC News Yoruba nibi ti oun ati akẹgbẹ rẹ,Abilẹkọ Dunni Badru ti salaye bi awọn ṣe bẹrẹ eto naa.
Ninu ifọrọwerọ naa ni wọn ti salaye nigba awọn ipenija ti awọn ti koju lasiko ti wọn ba n ṣe eto naa.
- 'Oṣù mẹ́sàn-án ni wọ́n fi jí mi gbé tí wọ́n ń fipá bá mi lòpọ̀ títí tó fi di oyún'
- 'Gbogbo ọlọ́pàá tó ń gbégidínà lọ́nà àìtọ́, ẹ yọ wọ́n kúrò'
- Mo fún òṣìṣẹ́ tó bá fẹ́ du ipò gómìnà di December 18 láti fi ipò tó wà sílẹ̀ - Gómìnà Fayemi
- Bí àdúrà ọjọ́ kẹjọ àti ayẹyẹ òkú Baba Suwe yóò ṣe lọ rèé
- Kókó méje tó wà nínú ‘White Paper’ ìjọba Eko lórí àbọ̀ ìwádìí ìwọ́de EndSARS
- Davido: Yinka Ayefele sọ ìrírí rẹ̀ pẹ̀lú olórin Davido tó fi ní kò dà bí àwọn ọ̀dọ́ olórin kan
Bakan naa ni wọn fi imoran lede fun awọn ọkọ ati iyawo lọna ati mu igbeyawo wọn gbooro si.
Ẹkunrẹrẹ wa ninu fidio yii...