FUTA first class twins: Ká ní pe àwa méjèèjì kò ní 'First Class'........- Taiwo Oluyori FUTA

Àkọlé fídíò, FUTA First Class Twins

Se e ranti awon ibeji ti wọn pegede julọ nibi ikẹkọgboye fasiti Federal University of Technology (FUTA) Akure.

Taiwo ati Kehinde Oriyale gbalejo BBC Yoruba, se ọmọẹni ko kuku se idi bẹbẹrẹ ki a wa ko ilẹkẹ si idi ọmọ ẹlo mii.

Taiwo ati Kehinde salaye kikun nipa irinajo aye wọn.

Wọn sọ diẹ lara awọn igbesẹ ti wọn gbẹ ti wọn fi le pegede ju awọn akẹgbe wọn lọ.

Bakan naa ni awọn ibeji yii sọ diẹ lara ohun ti oju Obi wọn ri ati lara awọn ipenija ti wọn koju.

Omowe Olufunke Akinola to jẹ adari ẹka imọ nipa ikọle ti awọn akẹkọọ naa ti ṣetan naa ba BBC Yoruba sọrọ lori ihuwasi wọn ninu ẹkọ ile ati ẹkọ iwe.

O sapejuwe awọn ibeji Oriyale gẹgẹ bi ọmọ ti wọn kọ to de gab ẹkọ.