Mr Macaroni sọ nípa eré tí Freaky Freaky, Sugar Daddy, You are doing well, Freaky Spicy fẹ́ran láti máa ṣe
Mo jẹ oniwaasu lori ọrọ ifẹ lọjọkọjọ- Mr Macaroni
BBC Yoruba gbalejo alawada adẹrinpoṣonu ni Mr Macaroni
Oun naa ni Freaky Freaky, ti wọn tun n pe ni Sugar Daddy, Freaky Spicy, ati You are doing well.
Ohun marun un ree ti awọn eeyan ko mọ nipa Mr Macaroni.
- Ǹkan tí ó yẹ ki o mọ̀ nípa Burna Boy
- Ilé ẹjọ́ ju ọmọ ìjọ tó fi ìpá bá ọmọ pásítọ̀ rẹ̀ sùn ní ìpínlẹ̀ Ondo sí ẹ̀wọ̀n gbére
- Tinubu ni bàbá mi, àyẹ̀wò DNA wà; mo ni ìwé ẹ̀rí àti àwọn ǹkan míì tí Tinubu sọ ní Chattam House
- Aya àti ọ̀rẹ́ kọ̀ mí sílẹ̀ lẹ́yìn ti mo pàdánù ẹ̀sẹ̀ mi ṣùgbọ́n mo kọ̀ láti ṣagbe ni mo ṣe padà síṣẹ́ wẹ́dà- Yussuf
Mr Fabulous tun mẹnuba asiko to maa ṣe igbeyawo pe ko i to nitori oun ko ni obinrin afẹsọna rara.
- Àì sí isẹ́ fáwọn ọ̀dọ́ jẹ́ ọ̀kan gbòógì tó fà ìgbésùnmọ̀mí ní ẹkùn àríwá ìwọ̀ oòrùn- Peter Obi-
- Báwo ní àwọn agbébọn ṣe palẹ̀mọ́ àwọn olùjọ́sìn ní Mọ́ṣáláṣí ni Ìpínlẹ̀ Katsina-
- Ilé ẹjọ́ ju olè orí omi mẹ́ta sí ẹ̀wọ̀n, ó tún ní kí wọ́n san 60 miliọ̀nù
- Abọ́ fífọ̀ àti ilẹ̀ ọkọ̀ ojú omi ní gbígbá ní mó fi kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́- Victor Agunbiade


