Royal Hugs Surprises, Women: Ìyá ẹni ọdún 50 tó dọlọ́mọ láyé fi ìdùnnú hàn bí a ṣe kàn síi- Deborah Toyin Oyesanya

Àkọlé fídíò, Royal Hugs Surprises: Ìyá ẹni ọdún 50 tó dọlọ́mọ láyé fi ìdùnnú hàn bí a ṣe kàn síi- Debor

Deborah Oluwatoyin Oyesanya: Mi o ba ti pa ra mi bikoṣe pe ẹnikan fun mi ni akara oyinbo.

Ọpọ eeyan to n rin ni titi ni inu wọn ko dun.

Opọlọpọ lo wa ninu ibanuje sugbọn ti wọn n rẹrin kiri ni agbaye.

Deborah Oluwatoyin to jẹ oludari Royal Hugs Surprises sọ irir ara rẹ ati bi akatra oyinbo ṣe jẹ ko ma pa ara rẹ mo.

Oyesanya

Deborah Oyesanya menuba ayọ to kun ọkan awọn eeyan ti ololufẹ wọn ti ṣeto iyalẹnu lọjọ ibi wọn, nibi ikomọjade ati bẹẹ bẹẹ lọ.

Oyesanya

O mẹnuba bi oun ṣe bẹrẹ iṣẹ yii lai kọkọ maa gba owo lọwọ awọn ti oun n ṣe e fun lọfẹ ṣugbọn ki wọn maa gbe e sori ayelujara.

Oluwatoyin Royal Hugs Surprises salaye fun BBC pataki lilo ayelujara lasiko yii.

Bakan naa lo gba ijọba Naijiria niyanju lati ma fofin de 'Socal Media'nitori nibẹ ni ọpọ ọdọ laye ode oni ti n ṣiṣẹ ti wọn si n san owo ori si apo ijoba.

Oyesanya