You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Sound City MVP: Naira Marley, Burna Boy àti Rema ló kó àmì ẹ̀yẹ tó pọ̀jù
Burna Boy ni olorin to gba ade to pọju lọ ninu eto ifami ẹyẹ dani lọla ti Sound City MVP tọdun 2020.
Oun lo gba ọmọ Adulawọ to pegede julọ ninu awọn olorin.
Awọn miran to tun gba ami ẹyẹ ni Tẹni, Tiwa Savage, Naira Marley, Davido ati Rema.
Lọjọ Abamẹta ni ifami ẹyẹ dani lọla naa waye ni alẹ ni Eko Convention Center nipinlẹ Eko ni guusu Naijiria
Tiwa Savage, Diamond Platnumz, Big Tril atawọn olorin miran kọrin fawọn ero nibi ayẹyẹ naa
Bonang Matheba, sọrọsọrọ ori afẹfẹ to jẹ ọmọ orilẹ-ede South Africa lo gab alejo eto naa.
Awọn ti wọn gba ami ẹyẹ ninu awọn olorin ilẹ Adulawọ ni yii:
Awọn tuntun to pegede julọ ni MVP:
FireBoy DML (NG)
JoeBoy (NG)
Marioo (TZ)
Rema (NG) - Ẹni to jawe olubori
Simmy (SA)
Wendy Shay (GH)
Awọn ti wọn jọ fowọsowọpọ to pegede julọ:
Blow My Mind - Davido [NG]
Daz How Star Do - Skibii [NG]
Gugulethu - Prince Kaybee [SA] - Ẹni to pegede julọ
Jama - DJ Mic Smith [GH]
Killin Dem - Burna Boy [NG]
Inama - Diamond PlatNumz [TZ]
Olorin takasufẹ to pegede julọ:
Innos B [CG]
Nandy [TZ]
JoeBoy [NG] - Ẹni to jawe olubori
Otile Brown [KE]
Kizz Daniel [NG]
Teni [NG]
Mayorkun [NG]
Rayvanny [TZ]
Naira Marley [NG]
- Amotekun kò ní gbé ìbọn o! kíni wọn yóò máa ṣe ní ìpínlẹ̀ - DAWN Commission
- Ẹ kò nílò nọ́mbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020 - JAMB
- Pósí tí wọn ń tà lẹ́nu ọ̀nà ilé ìwòsàn àpàpọ̀ ló ń tètè pa wá - Aláìsàn figbeta
- Ṣo mọ̀ pé J.F Odunjo jẹ aṣòfin àti mínísítà nílẹ̀ yìí, yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ òǹkọ̀wé?
Olorin alujo to pegede julọ:
BlaqBonez (NG)
Falz (NG)
KHALIGRAPH Jones (KE) - Ẹni to jawe olubori
Kwesta (SA)
Medikal (GH)
Shinski (KE)
Sarkodie (GH)
Reminisce (NG)
Ricky Rick (SA)
Zakwe (SA)
Awọn meji ti wọn fọwọsowọpọ to pegede julọ:
Black Motion (SA)
Blaq diamond (SA)
DopeNation (GH) - Ẹni to jawe olubori
Ethic (KE)
Show Dem Camp (NG)
Toofan (TG)
Olootu ilẹ Adulawọ to pegede julọ
Cracker (NG)
Prince Kaybee (SA)
Jay Synth (NG)
Kel P (NG)
MOG (GH)
Ozedikus (NG)
Pheelz (NG)
Rexxie (NG) - Ẹni to jawe olubori
S2Kizzy (TZ)
Olorin obinrin MVP to pegede julọ
Daphne (CMR)
Nandy (TZ)
Sho Madjozi (SA)
Teni (NG) - Ẹni to jawe olubori
Tiwa Savage (NG)
Yemi Alade (NG)
- Ìjọba Ondo, inú fìfo la fi ń ṣiṣẹ́, ẹ ṣan ọ̀pọ̀ owó oṣù tẹ jẹ wa - Àwọn dókítà fárígá
- Ilé ẹjọ́ pàṣẹ kí wọ́n fi àwọn afurasí tó pa àkẹ́kọ̀ọ́ LASU sí ẹ̀wọ̀n
- Obìnrin Kwara tí wọ́n tà sóko ẹrú ní Lebanon figbe ta, ọwọ́ tẹ èèbó kọ̀ráà tó ṣiṣẹ́ náà
- Ǹjẹ́ ọmọ Buhari lásẹ láti wọ Ọkọ̀ òfúrufú Nigeria Air force 1 lọ sí òde?
Olorin ọkunrin MVP to pegede julọ
Burna Boy (NG) - Ẹni to jawe olubori
Davido (NG)
Diamond Platnumz (TZ)
King Promise (GH)
Sjava (SA)
Wizkid (NG)
Zlatan (NG)
Ato orin pọ to pegede julọ nilẹ Adulawọ
DJ Creme De La Creme (KE)
DJ Kaywise (NG)
DJ Neptune (NG)
DJ Spinall (NG) - Ẹni to jawe olubori
DJ Vyrusky (GH)
DJ Zinhle (SA)
Olorin igbalode ayarabiasa to pegede julo:
Cassper Nyovest [SA]
Davido [NG] - Ẹni to jawe olubori
Diamond Platnumz [TZ]
Kizz Daniel [NG]
Mr Eazi [NG]
Yemi Alade [NG]
Wizkid [NG]
Ẹni ti awọn eniyan n gbọ orin ré julọ
Baby - JoeBoy (NG)
Dumebi - Rema (NG)
Fetch your Life - Prince Kaybee (SA)
Jealous - Fireboy DML (NG) - Ẹni to jawe olubori
Jama - DJ Mic Smith (GH)
Kainama - Harmonize (TZ)
Killin Dem - BurnaBoy (NG)
Kpo K3K3 - StoneBwoy (GH)
Oil & Gas - Olamide (NG)
Ẹni ti awọn onworan n wo julọ
49-99 - Tiwa Savage (NG)
Able God - Chinko Ekun (NG)
Banomoya - Prince Kaybee (SA)
My Level - Shatta Wale (GH)
On The Low - Burna Boy (NG)
Soapy - Naira Marley (NG) - Ẹni to jawe olubori
Tetema - Rayvanny (TZ)
Zanku (Legwork) - Zlatan (NG)
Fọnran fidio ti awọn eniyan wo julọ
49-99 - Tiwa Savage by Meji Alabi (NG) - Ẹni to jawe olubori
Dangote - Burna Boy by Clarence Peters (NG)
Jericho - Simi by Adasa Cookey (NG)
Ngwa - Blick Bassy by Tebego Malope (SA)
Ohema - Kuami Eugene by Rex (GH)
Orin ti o dun julọ lọdun:
Jealous - FireBoy DML (NG)
Killin Dem - Burna Boy (NG) - Ẹni to jawe olubori
Malwhede - King Monada (SA)
Soapy - Naira Marley (NG)
Tetema - Rayvanny (TZ)
Zanku (Legwork) - Zlatan (NG)
Baby - JoeBoy (NG)
Case - Teni (NG)
Dumebi - Rema (NG)
Fetch Your Life - Prince Kaybee (SA)
Jama - DJ Mic Smith(GH)
Olorin tilẹ Adulawọ lọdun
Burna Boy (NG) - Ẹni to jawe olubori
Davido (NG)
Diamond Platnumz (TZ)
Shatta Wale (GH)
ShoMadjozi (SA)
Tiwa Savage (NG)
Wizkid (NG)
Yemi Alade (NG)
Alaṣeyọri ninu iṣẹ iranraẹnilọwọ: DJ Cuppy - Ẹni to jawe olubori
Alaṣeyọri ninu ere idaraya: Anthony Joshua - Ẹni to jawe olubori
Alaṣeyọri ninu iṣẹ aje ati idagbasoke ọna igbalode: Bright Jaja - Ẹni to jawe olubori
Alaṣeyọri ninu Idagbasoke ilu ninu iṣelu ati awujọ pẹlu agbegbe: Adebola Williams & Jude Jideonwo - Ẹni to jawe olubori
Alaṣeyọri ninu orin kikọ: Innocent Idibia (2Baba) - Ẹni to jawe olubori