Ooni Ogunwusi ti kọ̀ǹgọ́ bọ̀lù níbi Àjọ̀dún ìlú Ayangalu ní Ile Ife

Ọọni Ile Ifẹ n lu ilu nibi ajọdun ilu Ayangalu ni ile Ifẹ.
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ọpọlọpọ awọn ololufẹ ọrọ aṣa, awọn ọmọwe atawọn oniṣẹṣe ni wọn pejupesẹ si ilu ile Ifẹ lati ṣayajọ ọdun ilu Ayangalu .

Awọn onilu Ọọni Ile Ifẹ n lu ilu nibi ajọdun ilu Ayangalu ni ile Ifẹ.

Ọọni iluu IleIfẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusiclo lewaju ajọdun naa eyi ti wọn ni wọn gbe kalẹ lati fi ilu kona mọ ọrọ iṣọkan, alaafia ati igbeleke aṣa.

Ọọni Ile Ifẹ ati ọkan lara awọn olori rẹ nibi ajọdun ilu Ayangalu ni ile Ifẹ.
Awọn agba oye nibi ajọdun ilu Ayangalu ni ile Ifẹ.
Awọn obinrin kan n jo si ilu nibi ajọdun ilu Ayangalu ni ile Ifẹ.
Onilu kan n lu ilu nibi ajọdun ilu Ayangalu ni ile Ifẹ.
Awọn onilu n lu ilu nibi ajọdun ilu Ayangalu ni ile Ifẹ.