Àkójọpọ̀ orúkọ àwọn èèyàn 175 tí Ààrẹ Tinubu ṣe àforíjìn fún àti ẹ̀ṣẹ̀ tí wọn ṣẹ̀ tẹ́lẹ̀

Oríṣun àwòrán, Bayo Onanuga/X
Aarẹ Bola Tinubu ṣe aforijin fun ọpọ ọmọ Naijiria to wa lọgba ẹwọn ti n wọn faṣọ penpe roko ọba kaakiri ọgba ẹwọn ni Naijiria lọsẹ to kọja.
Oludamọran aarẹ lori ọrọ iroyin, Bayo Onanuga, lo fọrọ naa lede loju opo Facebook ati X re.
Ọriṣii isọri lawọn ẹlẹwọn ti Aarẹ Tinubu lo agbara rẹ lati ṣe aforijin fun, isọri kan lara wọn awọn ti wọn dero ẹwọn nipa gbigbe oogun oloro.
Awọn mii ri ẹwọn he lẹyin ti wọn jẹbi ẹsun wiwa kusa lọna aitọ, nigba tawọn mii di ẹlẹwọn lori ẹsun ipaniyan ti wọn jẹbi rẹ, ti awọn miran si gbe oogun oloro tẹlẹ.
Wọnyii ni akojọpọ gbogbo awọn ẹlẹwọn ti Tinubu ṣe aforijin fun ati ẹṣẹ ti wọn ṣẹ tẹlẹ:
- Nweke Francis Chibueze: gba idarijin lẹwọn gbere fun gbigbe ogun oloro cocaine
- Ọmọwe Nwogu Peters: to n ṣẹwọn ọdun ọdun mẹtadinlaadọrin fun jibiti lilu gba idarijin
- Arabinrin Anastasia Daniel Nwaoba: gba idarijin fun jibiti lilu
- Amofin Hussaini Alhaji Umar: gba aforijin lori ẹsun iwa ajẹbanu
- Ayinla Saadu Alanamu: ri aforijin aarẹ gba lori riba
- Farouk M. Lawan: gba aforojin lori iwa ajẹbanu
- Ọgagun Mamman Vatsa: gba idarijin bo tilẹ jẹ ijọba ologun pa a
Awọn ajijagbara Ogoni mẹsan an to ti ku gba aforijin aarẹ
- Ken Saro Wiwa
- Saturday Dobee
- Nordu Eawa
- Daniel Gbooko
- Paul Levera
- Felix Nuate
- Baribor Bera
- Barinem Kiobel
- John Kpuine
Aarẹ dawọn Oloye Ogoni mẹrin lọla
- Oloye Albert Badey
- Oloye Edward Kobaru
- Oloye Samuel Orage
- Oloye Theophilus Orage
Isọri awọn ẹlẹwọn mii to ri Aarẹ Tinubu ṣe aforijin fun
- Aluagwu Lawrence to wa lẹwọn fun igbo tita.
- Ben Friday to wa ẹlẹwọn fun igbo tita.
- Oroke Micheal Chibueze to dero ẹwọn fun tita ogun oloro Cannabis.
- Kelvin Christopher Smith to wa lẹwọn fun kiko cocaine wọle
- Azubuike Jeremiah Emeka - oogun oloro gbigbe
- Akinrinnade Akinwande Adebiyi to wa lẹwọn fun tita oogun Tramadol
- Ahmed Adeyemo to wa lẹwọn fun tita oogun oloro cannabis.
- Adeniyi Jimoh to wa lẹwọn fun oogun tita.
- Seun Omirinde to wa lẹwọn fun oogun oloro.
- Adesanya Olufemi Paul to wa lẹwọn fun idigunjale.
- Ife Yusuf ti n ṣẹwọn fun kata-kara.
- Daniel Bodunwa to dero ẹwọn lori iwe yiyi
- Fidelis Michael to wa lẹwọn fun oogun oloro tita
- Suru Akande – oogun oloro
- Safiyanu Umar – oogun oloro gbigbe
- Dahiru Abdullahi – kiko ibọn pamọ
- Hamza Abubakar - Igbo tita
- Rabiu Alhassan Dawaki – iwa ọdaran
- Mujibu Muhammad, - oogun oloro gbigbe
- Emmanuel Eze – oogun oloro gbigbe
- Bala Azika Yahaya – oogun oloro gbigbe
- Lina Kusum Wilson - ẹsun ipaniyan
Awọn mii to ri aforijin aarẹ gba
Buhari Sani
Mohammed Musa
Muharazu Abubakar
Ibrahim Yusuf
Saad Ahmed Madaki
Ex-Corporal Michael Bawa
Richard Ayuba
Adam Abubakar
Emmanuel Yusuf
Edwin Nnazor
Chinedu Stanley
Joseph Nwanoka
Johnny Ntheru
John Omotiye
Nsikat Edet Harry
Jonathan Asuquo
Prince Samuel Peters
Babangida Saliu,
Adamu Sanni
Abdulkarem Salisu
Abdulaziz Lawal
Abdulrahman Babangida
Maharazu Alidu
Zaharadeen Baliue
Babangida Usman
Zayyanu Abdullahi
Bashir Garuba
Imam Suleman
Abbeh Amisu
Lawani Lurwanu
Yusuf Alhassan
Abdulahi Isah
Zayanu Bello
Habeeb Suleman
Jubrin Sahabi
Shefiu Umar
Seidu Abubakar
Haruna Abubakar
Rabiu Seidu
Macha Kuru
Zahradeen Aminu
Nazipi Musa
Abdullahi Musa
Habibu Safiu
Husseni Sani
Musa Lawali
Suleiman Lawal
Yusuf Iliyasu
Sebiyu Aliyu
Halliru Sani
Shittu Aliyu
Sanusi Aminu
Isiaka Adamu
Mamman Ibrahim
Shuaibu Abdullahi
Sanusi Adamu
Sadi Musa
Haruna Isah
Abiodun Elemero
Maryam Sanda
Awọn ẹlẹwọn ti aarẹ sọ idajọ iku di ẹwọn gbere fun
- Emmanuel Baba
- Emmanuel Gladstone
- Moses Ayodele Olurunfemi
- Abubakar Usman
- Khalifa Umar
- Benjamin Ekeze
- Mohammed Umar
Oludamọran aarẹ lori ọrọ iroyin, Onanuga, ṣalaye pe Aarẹ Tinubu ṣe aforijin fawọn ẹlẹwọn naa latari iroyin to tẹ ẹ lọwọ wi pe wọn ti ronu piwa da.
Onanuga fikun ọrọ rẹ pe aarẹ darijin awọn kan ninu wọn nitori ọjọ ori wọn.
Awọn mii ri idarijin aarẹ lẹyin ti wọn ti kọ iṣẹ ọwọ kan tabi omiran lọgba ẹwọn ti wọn wa.
Bakan naa ni Ọgbẹni Onanuga tun ṣalaye pe Tinubu ṣe aforijin fun ajijagbara fun ominira orilẹede Naijiria, Herbert Macaulay, lati fi idajọ ododo mulẹ lẹyin ti ijọba amunisin Ilẹ Gẹẹsi lo jẹbi ẹsun iwa ajẹbanu lọna aitọ.















