Tí o bá fẹ́ di gómìnà Kogi, kàn sí àwa Àjẹ́ àti Oṣó .....Oboi

Aworan Dino melaye

Oríṣun àwòrán, @Others

Bi eto idibo sipo gomina ipinlẹ Kogi ti n sunmo ni iroyin kan jade pe awọn ẹgbẹ Ajẹ funfun ati awọn Oso ipinlẹ ọhun ti rọ ẹni ti ke si Dino pe ọrọ wa.

Iroyin to gba ayelujara kan naa sọ pe Won sọ fun ẹni ti o ti figba kan ri jẹ sẹnato fun ipinlẹ Kogi to tun n dije dupo Gomina ipinlẹ naa Dino Melaye lati yọju si wọn, bi bẹẹ kọ, ko mura lati padanu ninu eto idibo to n bọ.

Dino Melaye lo n dijẹ dupo gomina labẹ asia ẹgbẹ oselu PDP ni pinlẹ Kogi.

Iroyin naa sọ pe Agbẹnuso ẹgbẹ ọhun Dokita, Okhue Oboi lo fọrọ naa lede ninu atẹjade kan.

Okhue ni “ati ṣe ipade pọ pẹlu eeyan ti ẹya Igala, Ebira ati awọn Yoruba to wa ni ipinlẹ ọhun,

A pade awọn ara Igala ni Idah,Ebira ni Obehira ati awọn Yoruba to wa ni Kabba”.

“A rọ Dino Melaye lati ri wa to ba fẹ bori gẹgẹ bi gomina ti wọn dibo yan.

To ba gbo si wa lẹnu yoo rẹrin nitori gbogbo awọn igi ati omi ipinlẹ Kogi ni yoo dibo fun bi gomina Wike baa kọ lati se atilẹyin fun”.

Tinubu la dibo yan ninu ẹgbẹ awa Ajẹ.

Oboi ni awọn ẹgbẹ Ajẹ ti pese ọmọ ẹgbẹ to to ọọdunrun ni yen lati pese aabo to daju fun Bola Ahmed Tinubu ṣaaju eto ibura fun aarẹ tuntun.

O tẹsiwaju wi pe ẹgbẹ awọn Aje ati Oso ko dun nu si bi awọn oloselu kan ti n wuwa lati gba ti Bola Tinubu ti jawe olubori gẹgẹ bi aarẹ Orilẹede yii lati inu osu keji ọdun yii.

Nigba ti oun ki Bola Tinubu kaabọ pada si Orilẹede yii lẹyin isinmi to lọ fun loke okun ,

Oboi ni osu meji ṣaaju eto idibo apapọ Orilẹede yii ni Bola Tinubu ti jawe olubori ninu eto idibo ẹgbẹ awọn Ajẹ ati Oso.

Wọn rọ awọn to padanu ninu eto idibo to koja lati fọwọ wọnu ki gbogbo eeyan gbadura ki Bola Tinubu ni alafia ati ẹmi gungun ko lẹ mu ileri to sẹ nigba ipolongo ibo sẹ.

Oͅwóͅ teͅ ìyá tí wón fi èͅsùn kàn pé ó pa oͅmoͅ oͅdún méjì rèͅ tó sì jẹ éͅ

Aworan

Oríṣun àwòrán, Citizen Kenya

Oͅdoͅbinrin kan ti wa ni atimoͅle oͅloͅpaa ni Kenya leͅyin ti woͅn fi eͅsun kan an pe o pa oͅmoͅ reͅ, oͅmoͅ oͅdun meji to si jeͅ lara reͅ.

Ileesͅeͅ oͅloͅpaa ni Kitengala, Kenya ni awoͅn n gbe obinrin naa loͅ si ileeͅjoͅ lori eͅsun pe o pa oͅmoͅ inu ara reͅ.

Arabinrin oͅhun ni woͅn gbe digba-digba loͅ si ileewosan leͅyin isͅeͅleͅ to sekoͅlu si oͅmoͅ inu ara reͅ ti awoͅn ara adugbo si ka isͅeͅleͅ naa si ori foonu woͅn.

Ninu ifoͅroͅweroͅ kan ti woͅn se peͅlu reͅ ni oͅjoͅ Aje, ki woͅn to gbe loͅ si ileesͅeͅ oͅloͅpaa lo ni ni nitori oun korira ara oun ni oun se sekupa oͅmoͅ oun.

O ni iya to n jeͅ oun ti poͅju, o ni ilakoͅja naa koͅja keremi, ni oun se hu iru iwa beͅeͅ amoͅ ko soͅ iru ilakoͅja naa.

Arabinrin Kaserran naa to tun jeͅ akeͅkoͅoͅ ipele keͅrin ni fasiti ni ara oun ni oun koͅkoͅ feͅ pa, ki oun to yi oͅkan pada, ti oun si gun oͅmoͅ oun pa ni oͅpoͅloͅpoͅ igba.

Awoͅn ara adugbo soͅ ohun ti oju woͅn ri

Skip podcast promotion and continue reading
Èyí ni ìkànnì Whatsapp wa

Àjáàbalẹ̀ ìròyìn BBC News Yorùbá lórí WhatsApp rẹ

Darapọ̀ mọ́ wa nibì

End of podcast promotion

Lasiko ti obinrin naa se ikoͅlu si oͅmoͅ reͅ ni awoͅn ara adugbo n wo bi o se n hu iwa ipaniyan yii.

Woͅn ni arabinrin naa gun oͅmoͅ naa ni oͅbe, o si la inu reͅ

Awoͅn aradugbo ni awoͅn sa kira loͅ si ile obinrin naa nigba ti awoͅn beͅreͅ si ni gboͅ ariwo, ti awoͅn si ro pe awoͅn oͅdaran lo n sekoͅlu si ile reͅ , amoͅ ti o jeͅ iyaleͅnu fun woͅn nigba ti woͅn de oju ferese ti woͅn ri pe oun lo n sekoͅlu si oͅmoͅ ara reͅ

Woͅn ni Kaserran gun oͅmoͅ naa ni oͅbeͅ ti o si n koͅ orin inu iwe mimo ti awoͅn ara adugbo si n wo.

Nise lo ti ileͅkun moͅ oun ati oͅmoͅ naa si inu ile ki o to beͅreͅ ikoͅlu naa.

Nigba ti awoͅn ara adugbo gbiyanju lati si ileͅkun eͅyin ti woͅn sib a oͅmoͅ naa, o ti doloogbe, ti iya naa si ti subu lu ileͅ.

Arabinrin naa ti da gbogbo inu ile ru, ti gbogbo ohun ini ti woͅn si ni sinu ile ti daru.

Arabinrin kan ti iseͅleͅ naa se oju reͅ ni oͅmoͅ oͅdun meji naa n pariwo orukoͅ iya reͅ.

Ileesͅeͅ oͅloͅpaa to n risi iwa oͅdaran ni awoͅn yoo gbe obinrin naa loͅ si ileeͅjoͅ leͅyin ti woͅn ba pari iwadii woͅn.

‘’Nise ni obinrin naa jeͅ eͅdoͅ oͅmoͅ reͅ ti awoͅn si n wo bi o se n hu iwa naa.’’