Èrò àwọn ọmọ Naijiria ṣọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ bí EFCC ṣe lu ọkọ̀ 435 tí wọ́n gbẹ́sẹ̀lé ní gbàǹjo

Oríṣun àwòrán, @officialEFCC
Ajọ to n gbogun ti iwa ajẹbanu ni Naijiria, EFCC ti bẹrẹ si ni lu ọkọ ti iye rẹ jẹ irinwo ati marundinlogoji ni gbanjo nipinlẹ Eko.
Awọn ọkọ naa jẹ eyii ti wọn gba lọwọ awọn ti ile ẹjọ paṣẹ pe ki wọn gbẹsẹle.
Ninu atẹjade kan ti EFCC fi lede loju opo Twitter rẹ, o ni wọn gbẹsẹle awọn ọkọ ọhun ni ibamu pẹlu ofin ti wọn gbe kalẹ lọdun 2004, ti ọdun 2007 ati 2022, eyii to fun awọn lasẹ lati ṣe bẹẹ.
Wayii o, ọpọ awọn araalu lo ti bẹrẹ si n fi erongba wọn lede lẹyin ti EFCC bẹrẹ si n ta awọn ọkọ naa ni gbanjo faraalu.
Ki ni awọn eeyan n sọ?
Bi o tilẹ jẹ pe ọpọ eeyan lo yọju sibi ti wọn ti n lu awọn ọkọ naa ni gbanjo, pupọ ninu wọn lo n sọ pe wọn ko ṣe eto naa daadaa.
Bakan naa lawọn mii n sọ pe ọkọ ti EFCC n lu ni gbanjo ti kọṣẹ, ko si yẹ ki wọn maa ta iru rẹ faraaalu.
Bankole Toyin sọ loju opo Twitter rẹ pe inu rugudu ni eto ọhun ti waye nigba to yẹ ki wọn ṣe daadaa.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Ni ti Cosmas Agubuzu, o ni yatọ si ọfiisi EFCC, o yẹ ki awọn araalu le maa wo bi gbanjo naa ṣe n lọ lori ẹrọ amohunmaworan, to si yẹ ki wọn pese nọmba ti awọn to ba ri ọkọ ra san owo si.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2
Bẹẹ naa ni awọn mii gbagbọ pe ọjọ ti lọ lori awọn ọkọ ti EFCC lu ni gbanjo, ko si tọ ki wọn ta wọn faraalu mọ.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 3
Awọn nnkan mii ti awọn eeyan n sọ ree
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 4

End of X post, 5

End of X post, 6

End of X post, 7

End of X post, 8