Àkọlé àwòrán, Awọn iyawo ile tilẹ ni awọn gbera lọ si Eko lati lọ bere pe bawo ni eto yoo ṣe jẹ ṣugbọn wọn ko jẹ ki awọn ri iyawo Wolii Joshua.
Àkọlé àwòrán, Àwọn obìnrin Akoko ní kò sí ọmọbíbí ilẹ̀ náà tó tọ́jú àwọn bíí olóògbé
Àkọlé àwòrán, Awọn Iyalaje ati Iyalọja ni ilẹ Akoko nipinlẹ Ondo ti pinnu lati ti gbogbo awọn ọja pa ni ọjọ Ẹti.
Àkọlé àwòrán, Atẹjade lati ọdọ Iyalaje ti ilu Ikarẹ-Akoko, Alhaja Risikat Mohammed sọ pe awọn ṣe bẹẹ lati bu ọla fun ọmọ wọn to ku.
Àkọlé àwòrán, O ni eyi yoo tun fun wọn ni anfaani lati wo bi eto isinku naa ba ṣe n lọ lori ẹrọ amohunmaworan ijọ Synagogue, Emmanuel TV.
Àkọlé àwòrán, Ẹlomii, to jẹ olori fun gbogbo awọn obinrin to jẹ oye ni ilẹ Akoko, Oloye Margaret Ebun Oladunni sọ pe ọsẹ ọfọ ni ọsẹ yii jẹ fun ilẹ Akoko.
Àkọlé fídíò, 'Ẹ má jẹ́ kí òkú ọmọ mi ráre o ìjọba! Ẹ gbée fún mi kí n lọ sin ín - Ìyá ọmọ ti wọ́n pa ní ìwọ́de Yoruba Nation