Dilip Kumar: Àgbà ọ̀jẹ̀ òṣèré India kú lẹ́ni ọdún méjìdinlọ́gọ́run

Dilip Kumar, ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn tó ń ṣe sinima, to sì gbajúgbajà ni India kú ní Mumbai lẹ́ni ọdún méjìdinlọ́gọ́run
Dilip Kumar àti Saira Bano aya rẹ tí kópa nínú sinimá àgbéléwò India lọ́pọ̀lọpọ̀.
Awọn sinima marunlelogọ́ta láàrin àádọ́ta ọdún lọ tí ṣe, tó sì máa ń kó àwọn ipa tó lágbára gidi.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ẹ wo obìnrin tó pàdé ọkọ́ lẹ́ni ọdún 47 , tó sì bímọ lẹ́ni àádọ́tá ọdún
- Hàà! Yomi wàá ṣẹ̀wọ̀n o! Oò ṣe bí ọlọ́pọlọ rárá, ò kàn ń fi àṣírí Baba Ijesha àti Iyabo Ojo gòkè ni - Femi Branch
- Àwọn alátìlẹyìn Sunday Igboho ṣe ìwọ́de ní Ibadan, wọ́n tọrọ nkan márùn-ún lọ́wọ́ Olubadan
- Ọlọ́pàá ní Aiye Confraternity rugi oyin tó bá ṣ'ayẹyẹ "7/7" l'Eko
- Ìdí rèé tí àwa lọ́balọ́ba fi dákẹ́ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù Sunday Igboho - Oluwo tí Iwo
- Àwọn olólùfẹ́ Baba Ìjèsà gbé ìgbà Gofund Me láti ràn án lọ́wọ́ sàn owó tí yóò fí ṣé ẹjọ́
- Sàdáńkátà! Ẹ̀yin ẹ̀létò ààbò, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ yín fún ìkọlù sí ilé Sunday Igboho - Ààrẹ Buhari
- Láéláé! A ò faramọ́ àbá àwọn Gómìnà Gúúsù pé ààrẹ Nàìjíríà gbọdọ̀ wá láti ẹkùn wọn lọ́dún 2023 - Ẹgbẹ́ Arewa
Ọgbọ́n ọjọ́ oṣù kẹfà ọdún ni wọ́n gbé lọ sí ilé ìwòsàn lẹ́yìn tó sọ pé òun kò lè mi daada.
Fún ìgbà díẹ̀ sí àsìkò yìí, ni ó ti ń ṣe àìsàn, tó sì ti ń lọ sí ilé ìwòsàn bọ̀ ni àìmọye ìgbà.

Ìyàwó rẹ Saira Banu, toun naa jẹ́ òṣèré Nollywood ló fi silẹ lọ, àwọn òṣèré méjèèjì kò bímọ sáyé.
Thackeray àti àwọn gbajúgbajà òṣèré Nollywood, to di mọ Shah Rukh Khan àti Ranbir Kapoor, lo sàbẹ̀wò sí ẹbí Kumar láti lọ bá ẹbi rẹ dárò.
Ọdún 1944 ló kọ́kọ́ ṣe sinimá rẹ, Jwaar Bhata, ṣùgbọ́n ọdún 1949 ni sinima rẹ, Andaz, to gbé jáde di ilúmọ̀ọ́ka.
"Lai dènà pẹnu Dilip Kumar jẹ́ òṣèré tó dára jù lọ tí India ni.
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn òṣèré mìíràn tún wà tó lókìkí julọ, ṣùgbọ́n òun ló dára jù. Gẹ́gẹ́ bí o sẹ sọ fún BBC.

Oríṣun àwòrán, Twitter@NFAIofficial
Ọ̀pọ̀ àwọn sinima to tí ṣe ni, Mela Naya, Daur, GangaJumna, Devdas àti Mughal-e-Azam ti wọn jẹ́ àwọn sinima àrà ọ̀tọ̀ tó jẹ́ kí àwọn olólùfẹ́ rẹ túbọ̀ fẹ́ràn rẹ.
Àwọn sinima mìíràn tí Kumar tí kọ ni Villager, suave urbanite, a Bengali gentleman àti Swashbuckling hero, kí ó tó di àsìkò tó wà lọ ń se sinima to tí ń kópa bii àgbàlagbà ni ọdún 70s, bí Ogbeni Desai ṣe sọ.
Kumar gba ẹ̀bùn àmin ẹ̀yẹ to ga julọ fún sinima, àti àmì ẹ̀yẹ tó ga julọ fún ará ìlú ni India.
Ó fẹ́ Saira Bano lọ́dún 1966, àwọn méjèèjì jọ kọ́pa nínú àwọn sinima to lókìkí lọpọlọpọ ìgbà. Ọdún 1998 ni Kumar tí ṣe sinima Kẹ́yìn.
Ọdún 1944 ló kọ́kọ́ ṣe sinimọ́ rẹ Jwaar Bhata, ṣùgbọ́n ọdún 1949 ni sinimọ́ rẹ Andaz t gbé jáde tọ si di ilúmọ̀ọ́ka.
"Lai dènà pẹnu Dilip Kumar jẹ́ òṣèré tó dára jù lọ tí India ni.
Bótilẹ̀ jẹ́ pé àwọn òṣèré mìíràn tún wà tó lókìkí julọ, ṣùgbọ́n òun ló dára jù. Gẹ́gẹ́ bí o sẹ sọ fún BBC
Ọ̀pọ̀ àwọn sinima to tí ṣe ni, Mela Naya, Daur, GangaJumna, Devdas àti Mughal-e-Azam jẹ́ àwọn sinima àrà ọ̀tọ̀ tó jẹ́ kí àwọn olólùfẹ́ rẹ túbọ̀ fẹ́ràn rẹ.
Àwọn sinima mìíràn tí Kumar tí kọ ni Villager, suave urbanite, a Bengali gentleman àti Swashbuckling hero, kí ó tó di àsìkò tó wà lọ ń se sinima to tí ń kópa àgbàlagbà ni ọdún 70s bí Ogbeni Desai ṣe sọ.
Ó gba ẹ̀bùn àmin ẹ̀yẹ to ga julọ fún sinima, àti àmì ẹ̀yẹ tó ga julọ fún ará ìlú ni India.
Ó fẹ́ Saira, Bano lọ́dún 1966, àwọn méjèèjì jọ kọ́pa nínú àwọn sinima ro lókìkí lọpọlọpọ ìgbà. Ọdún 1998 ni Kumar tí ṣe sinima Kẹ́yìn.
















