India, Coronavirus: Ìtọ́jú aláìsàn ló jẹ́ mi lógún nítorí ètò ìlera wa mẹ́hẹ- Nọ́ọ̀sì Kamala Nepali
Kamala Nepali ba BBC sọrọ lori nkan to jẹ ki oun pinnu lati maa tọju alaisan coronavirus lẹyin ti oun naa kagbako ẹ.
Kamala jẹ ọkan lara awọn nọọsi to n tọju awọn alaisan Coronavirus.
Nepali sọ bi oun funra oun ṣe ni ajakalẹ arun coronavirus ki o to yee bọ ti o si gbadun.
- Saudi Arabia, Iran àti Egypt wà lára orile-ede àgbáyé tó ga jùlọ láti fi ikú ṣe ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ lọ́dún 2020
- Àwọn Olùkọ́ Akure pegedé lórí ètò Akomolede àti Aṣa lórí BBC Yorùbá
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ni akẹ́kọ̀ọ́bìnrin fásítì Akungba l'Ondo gbẹ̀mí ara rẹ̀?
- Ṣé ǹkan oṣù rẹ ń dà hìì hìì lẹ́yìn tóó gba abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19? Ẹ gbọ́ tuntun lẹ́nu àwọn Dókítà
- Irọ́ ni pé àwọn ajínigbé ń bèèrè fún N30m láti tú pásítọ̀ Deeper Life sílẹ̀- ọmọ pásítọ̀
- Ẹ̀yìn tí ẹ̀ ń pè fún Yoruba Nation, òpè ní yín, ẹ kò ní ìmọ̀- Ladoja
- Aàrẹ Joe Biden sọ̀rọ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́ lórí ìja Isreal àti Palestine
Kamala salaye kikun nipa bi oun ṣe pinnu lati maa ṣetọju awọn alaisan Covid 19 nitori pe oun mọ bi o ṣe n ri lara lati wa ni ẹsẹ kan aye ati ẹsẹ kan ọrun.
Nọọsi ẹni ọdun merinlelogun yii yanana ni kikun lori ohun ti itọju alaisan Covid 19 le gba lọwọ olutọju rẹ.
- ''Àwa àgbààgbà òṣèré kò dákẹ́ lórí wàhálà láàrin Iyabọ Ojo ati Yomi Fabiyi nitori Baba Ijẹsha''
- Ìjá tó ń lọ́ láàrin ilẹ̀ Israel átí Palestian kò bá wa lára mú, ó ń kọwálọ́minú- Ìjọba Naijiria
- ICPC ń wá ọkọ ọmọ Buhari àtàwọn méjì míì lórí ṣíṣe $65,000,000 kúmọ kùmọ
- 'Nígbá tí a rí Baba Ijesha lónìí ní Panti, ohun tójú wa rí, ẹnu kò lè sọ o!'
- Wo bí Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ṣe wo ilé àti Ìsọ Pákó lábẹ́ afárá Iganmu
- Àwọn eèyàn kan fara gbọta níbi ìjà àwọn Aṣọ́bodè àti Ònífàyàwọ́ nígboro Iseyin lọ́jọ́ ọdún