Sunday Igboho: Seriki Fulani àti ẹbí rẹ̀ gba inú igbó dé ìpínlẹ̀ Ogun
Yatọ si ọmọ Seriki, BBC ri iyawo akọkọ Seriki Fulani, arabinrin Mariam ti wọn ṣe leṣe to si n gba omi sara.
Lasiko ti BBC bẹ obinrin naa wo, apa kan ori rẹ la ri ti wọn lẹ pilasita mọ oju ọgbẹ to wa lori rẹ.
Mariam ni inu yara oun ni awọn janduku kan to jẹ ẹya Yoruba wa ka oun mọ, ti wọn si sa oun ni ọbẹ lori.
- Ìfẹ́ Yorùbá ló mú mi fi ẹ̀mí wéwu láti kojú ajínigbé ní Kishi - Sunday Igboho
- N kò jà fún ìṣọ̀kan Yorùbá láti wá ipò tàbí orúkọ - Sunday Igboho
- Sunday Igboho sọ̀rọ̀ lórí ohun tó kan fún ilẹ̀ Yorùbá lọ́dún 2021
- Wo ìgbésẹ̀ tí àwọn lọ́balọ́ba, ọlọ́pàá àti Seyi Makinde fẹ́ gbé lórí áàwọ Ibarapa
- Mo ń padà bọ̀ ní Ibarapa lọ́sẹ́ tó ń bọ̀- Igboho; Gbogbo dúkìá mi làwọn ọmọ Igboho jó tán- Seriki Fulani
- Wo ǹkan mẹ́fà tó yẹ kí o mọ̀ nípa Sunday Igboho tí orúkọ rẹ̀ gbẹnu aráyé kán
- Ó tó gẹ́! Ọ̀gá Ọlọ́pàá pàṣẹ pé kí Kọmísọ́nnà Oyo mú Igboho wà sí Abuja
- Igboho vs Fulani: Báyìí ni nǹkan ṣé ń lọ nílé Sunday Igboho lónìí
- Wo ohun tí BBC rí nílé Seriki Fulani ní Igangan
- ''Ìjọba ìpínlẹ̀ Ondo kò bẹ̀rù idúnkokò mọ́ni iléeṣẹ́ ààrẹ lórí ọ̀rọ̀ àwọn Fulani darandaran''
Bi o tilẹ jẹ pe a gbiyanju lati ba Mariam, aya Seriki Fulani naa sọrọ, amọ ko le e sọrọ daadaa ju pe o darukọ rẹ fun wa lọ.