EndSars, EndSwat: Ọlọ́pàá ti fi ìbọn lù mí láyà rí torí mó ní 'extra tyre' méjì- afẹ́hònúhàn
Opọ oluwọde sọrọ ilẹ kun lori ọrọ Endsars ati EndSwart ti wọn fẹ ki ijọba wa ojutu si lati gbogun ti ifiyajẹni lọna aitọ to n ṣẹlẹ si awọn eniyan Naijiria lati ọwọ awọn agbofinro.
Awọn osere ati alawada bii: Yomi Fabiyi, Jigan, Mr Macaroni atawọn èèyan fariga lori ọrọ ifiyajẹni lọna aitọ awọn agbofinro Naijiria.
Ọpọ n beere pe kini awọn oluwọde tun n fẹ lẹyin ti ijọba Buhari ti kede pe oun tu awọn ọlọpaa kogberegbe SARS ka.
- Àjọ DSS tú gbogbo pátá mi wò pé wọ́n ń wa ọmọ- Bisola aya Woli Alfa
- Wo ìlànà ìgbani síṣẹ́ márùn-ún fún àwọn ọlọ́pàá SWAT tó rọ́pò SARS
- Ọlọ́pàá mẹ́sàn án tó farapa nínú ìjàmbá ọkọ̀ Akure t'éèyàn méjì ti kú sì wà nílé ìwòsàn
- Ìjàmbá ọkọ̀ akérò àti tírélà pa èèyàn mẹ́rin lọ́nà mọ́rosẹ̀ Ore sí Benin
- Mo ṣèlérí láti ṣe ju ohun tí mo ti ṣe lọ fún ẹbí àwọn tó kú torí EndSARS - Seyi Makinde
Awọn oluwọde ni kii ṣe pe ki ijọba yi orukọ SARS pada si SWAT ni awọn beere fun bikoṣe pe ki ijọba foju awọn to huwa ibi han pẹlu idajọ to yẹ fun wọn.
Ki ijọba tun owo osu ọlọpaa ṣe pẹlu ilana ikọni gẹgẹ bi akọṣẹmọṣẹ agbofinro asiko yii ati bẹẹ bẹẹ lọ.

Awọn oluwọde salaye diẹ nipa awọn ohun ti wọn ti la kọja lọwọ awọn agbofinro sẹyin.Ìya Emma oní POS ṣẹ̀ṣẹ̀ rékọjá lọ síbí ilé yẹn ni àtọmọdé, ó sì wó pa wọ́n - Láńlọọ̀dù Obalende
Koda, wọn ni ija ṣẹṣẹ bẹrẹ ni titi ijọba Buhari yoo fi pese eto aabo to yẹ fun awọn ara ilu.

