Akure: Deji Akure, Oba Aladelusi Ogunlade ti pàṣẹ kí gbogbo ọjà wà ní títì pa fún ọjọ́ méjì nítorí àjọ̀dún ìṣẹ̀mbáyé méjì

Oríṣun àwòrán, DEJI of AKURE Kingdom
Deji ilu Akurẹ, Ọba Aladelusi Ogunlade ti kede pe ki Ọja gbogbo ni ilu Akurẹ o wa ni titi pa fun awọn ọjọ meji kan bayii.
Atẹjade kan lati ọdọ Kabiesi Deji ti ilu Akurẹ, eyi ti agbẹnusọ rẹ, Adeyẹye Michael fi sita fi idi rẹ mulẹ pe ni ọjọ kẹrinlelogun, oṣu kẹjọ ọdun yii ti ṣe ọjọ Aje to n bọ, ko ni si tita rira ni gbogbo ọja to wa ni ilu Akurẹ.
- Ọba Ilorin ló pàṣẹ pé kí ń padà sọ́dọ̀ ọkọ mi - Risikat olójú búlúù
- Kére o! Nàíjíríà tún ń wọnú ọrọ̀ ajé tó dagun lọ lẹ́ẹ̀kejì - Ìjọba àpapọ̀ laago ìkìlọ̀
- Afurasí mẹ́rin jí obìnrin oníṣòwò gbé ni Lanlate, wọ́n pa àfẹ́sọ́nà rẹ̀
- Bí ìyàwó rẹ bá lóyún tàbí bímọ ní ìpínlẹ̀ Oyo, wo bí o ti ṣe lé gba ìsinmi ìtọ́mọ (Paternity leave)
Bakan naa ni ọrọ yoo ṣe ri ni ọjọ kẹsan an, oṣu kẹsan an pẹlu.
Gẹgẹ bi atẹjade naa ṣe sọ, eredi igbesẹ ati ti ọja lawọn ọjọ ti a la kalẹ wọnyii wa lati lee fi sami ayajọ ọdun Aheregbe ati Amole.
Amọṣa o, wọn ni ajọdun naa ko ni di lils bibọ ọkọ ati ẹsẹ lọwọ.
- Ìgbà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí ìjọba Nàìjíríà ti gbẹsan lára orilẹ-ède mí tó dẹ́yẹsí i
- Ṣé o fẹ́ ṣiṣẹ́ ológun? Forúkọ sílẹ̀ nínú ìròyìn yìí
- Access Bank, dá ₦206,000 ìyá mi pádà lónìí, bí bẹ́ẹ̀ kọ́... Babaláwo yarí
- Kí ni ọkùnrin yìí ṣe tí bàbá rẹ̀ fi só mọ́lẹ̀ fún ọgbọ̀n ọdún?
- Wo àmúyẹ kí o tó lè di ọmọ ogun ilẹ̀ Nàìjíríà pẹ̀lú fọ́ọ́mù tó jáde yìí
- Làásìgbò òṣèlú wáyé nílùú Ondo, ọ̀pọ̀ èèyàn fara pa











