Bolanle Ninalowo: Fíìmù àkọ́kọ́ mi ló jẹ́ ẹṣin iwájú fún mi báyìí
Gbájúgbajà ni Bolanle Ninalowo, lóòtọ́ kò pẹ́ tó bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré Yollywood, inú rẹ̀ dún bí ó ṣe ti m'ókè.
Ninalowo jẹ́ ọmọ bíbí Ikorodu ní ìpínlẹ Eko.
Ó gbé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún ọdún mẹ́ẹ̀dógùn kó tó kó lọ sí Chicago ni orílẹ̀-èdè America níbi tí ó tún gbé fún ọdún mẹ́ẹ̀dógún mìíràn.
Bẹẹ ori lo mọ iṣẹ aṣela ni ọrọ eniyan ri, onikaluku kan n gbiyanju ni

Oríṣun àwòrán, @iamnino_b
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ara kìí ni ilẹ̀ tí koríko fi n hù, 2022 yòó san èmi àti ìwọ - Ọba Ogboni
- Wọ́n ti gbé Olubadan wọ káà ilẹ̀, bí ìsìnkú Ọba Adetunji ṣe lọ nìyí
- Ọdún tó súnmọ́ ìdìbò ni 2022, wọ́n kò ni ta ẹ̀jẹ̀ wa sílẹ̀
- Ogun ayé, ogun ọ̀tá kò ní borí rẹ lọ́dún tuntun - Woli Hezekiah
- Akíkanjú obìnrin Algeria tó kojú ogun Lárúbáwá fáwọn ènìyàn rẹ̀
Yàtọ̀ fún eré tíátà, ó tún ní ilé iṣẹ́ ọkọ̀ títà léyìí tó jẹ́ òwò ìdílé rẹ̀.
Bàbá rẹ̀ ti fi gbogbo ìgbà jẹ́ oníṣòwò ọkọ̀ òun sì ló fi iṣẹ́ náà lé òun àtàwọn ọmọ ìyà rẹ̀ lọ́wọ́.
Bolanle Ninalowo ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹ̀yẹ látàrí ìjáfáfá rẹ̀ nínú iṣẹ́ tíátà.

Oríṣun àwòrán, @Ninalowoofficial
Bolanle gba awọn ọdọ Naijiria ní imọran pẹ ki wọn tẹpa mọ iṣẹ ki wọn ma sọ ireti nu ti ọwọ wọn ko bai tii tẹ ohun ti wọn n le pa.
- Òṣèrébìnrin tí wọ́n bá fi ìbálòpọ̀ lọ̀ 'torí ìṣẹ́, kó bọ́ síta láti sọ̀rọ̀ - Kunle Afod
- Odunlade àti Femi Adebayọ: Wo ohun tó yà wá sọ́tọ̀ nínú àwọn arẹwà ọkùnrin
- Gbogbo àwọn tó ń gbé oúnjẹ́ wá fún mi ni mò ń fi iṣẹ́ búrukú rán sí Ọ̀gá Ọlọ́pàá, ìgbà tí mo ríi pé kò ràn wọ́n...- Ifasooto Dada
- Ṣé o mọ̀ ipò tí ìlú Owo l'Ondo ní ní Ààfin Ile Ife? Ẹ kálọ sí ìlú mi
- Àwọn ọmọ Nàìjíríà tó lọ sókè òkun ṣì ń padà bọ̀ wá sílé, àwọn òyìnbó gan an máa wá - Olórin Ayewa
- Iṣẹ́ tí Ọlọ́run kọ mọ́ mi ni mò ń ṣe -Ṣọla Ṣobọwale