Sheik Akeugbagold Taofeek: Ọdún tó súnmọ́ ìdìbò ni 2022, wọ́n kò ni ta ẹ̀jẹ̀ wa sílẹ̀ nínú 'Democracy'
Oriire inu 'Democracy' ni ko pin kan wa, a ko fẹ aburu inu idibo- Sheik Akeugbagold
Odun 2022 ni a mu yii, fun gbogbo ọkan to n ṣàìsàn, alaboyun, ati agan, ọdun itusilẹ yin ni 2022- Sheik Akeugbagold.
Eni to ba sọ pe Olorun kii gbọ adura n tan ara rẹ jẹ ni.
Ko dẹ si iṣoro to ni ibẹrẹ ti ko ni opin ti eeyan ba gbagbọ ninu Olodumare.
- Mo ti ra ilẹ̀ ìsìnkú mi ní 'Ebony Vault' ṣùgbọ́n....
- Wo bí àwọn gbajúmọ̀ tí ẹ̀ fẹ́ràn yìí ṣe tẹ̀ẹ́ wọ́nú ọdún 2022 àtí ohun t'Ọ́lọ́hun gbé wọn borí
- Àsọtẹ́lẹ̀ 2022 àti ìgbésẹ̀ tí Pásítọ̀ Enoch Adeboye fẹ́ gbé lórí ìdojúkọ Nàìjíríà nìyí
- Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ abàmì àti Kàyéfì tó wáyé lọ́dún 2021 rèé nínú fídíò
- Ohun tí CAN fi ṣíde ọdún 2022 fún gbogbo ọmọ Nàìjíríà nìyí
- Australia, New Zealand, Japan,àwọn orílẹ̀-èdè tó ti ṣáájú Nàìjíríà wọ ọdún 2022
Fi igabgbọ ṣe amin si adura ibẹrẹ ọdun 2022 ti Sheik Akeugbagold Taofeek ṣe pe o ko ni ba irinajo idibo ọdun to m bọ rin ni Naijiria .