New year prayers: Gbọgbọọgbọ lọwọ́ n yọ ju orí, gbogbo wa la ó yọ ju ọ̀tá wa lọ-Adeyinka Sangolade Oba Ogboni
Oba Ogboni Igba Iwase, Adeyinka Sangolade fi tọkan tara gbadura ọdun tuntun 2022 fun gbogbo ẹyin ololufẹ BBC Yoruba.
Ajibo ire ni Ifa
Arinakore ni Esu Odara
Gbogbo ololufẹ BBC Yoruba ni yoo rina ko ire lodun 2022.
Oba Ogboni tun gbadura fun awọn aṣiwaju Naijiria pe ki wọn maa mọ ọ ṣe lọdun tuntun yii.
- Iléewòsàn UCH kò lè bá Aafin Ibadan parọ́, ẹ dẹ́kún gbígbé ìròyìn òfegè nípa Oba Adetunji tó wàjà- Adeola Oloko
- Ogun ayé, ogun ọ̀tá kò ní borí rẹ lọ́dún tuntun - Woli Hezekiah
- Ọdún tó súnmọ́ ìdìbò ni 2022, wọ́n kò ni ta ẹ̀jẹ̀ wa sílẹ̀
- Agbọ́nmágbọ́ntán, Agọ̀mágọ̀jù, mọ̀ síi nípa àwọn orúkọ Ìjàpá nínú alọ àpagbè Yorùbá
- Ibi tí o bá dágbére fún ẹbí àti ará ní kí wọ́n ti ba ọ lásìkò ọdún Kérésì yìí- Akọ́ṣẹ́mọ́ṣẹ́ Bolarinwa
- Èmi kọ́ ló gbé orin ọdún ń lọ sópin kalẹ̀, CAC ló ni í ni mó n ṣe àkójọ orin- Fasoyin
- Wo bí ayẹyẹ òpin ọdún fún àwọn ọmọ Aláìníyá, Opó àti Àkàndá ẹ̀dá ṣe wáyé

