Prophet Hezekiah New Year Prayer: Gbogbo wa ni ká ṣiṣẹ́ fún ìdàgbàsókè Naijiria

Àkọlé fídíò, Prophet Hezekiah New Year Prayer: Gbogbo wa ni ká ṣiṣẹ́ fún ìdàgbàsókè Naijiria

Ajihinrere Agba fun ijọ Christ Apostolic Church, C.A.C, Wolii Hezekiah Oladeji ṣe adura ọdun tuntun fun awọn ọmọ Naijiria.

Ninu ojo adura to rọ le wọn lori lo tun ti gba wọn ni imọran pe ki ẹni kọọkan wọn mura, ki wọn o si ṣetan lati ṣiṣẹ fun idagbasoke orilẹ-ede Naijiria.

O ni ko si ajoji kankan to le tun Naijiria ṣe ju awọn ọmọ ilu lọ.