Alufaa Paul Tunde àti Favour Tioluwani lesekese: Má gbé àkàndá ọmọ tí ó bí pamọ̀ tàbí sọnù
Àwọn aláànú ṣe ọdún fáwọn tí kò rí ọwọ́ họrí
Wo bí ayẹyẹ òpin ọdún fún àwọn ọmọ Aláìníyá, Opó àti Àkàndá ẹ̀dá ṣe wáyé.
Alufaa Paul Tioluwani ṣalaye idi ti o fi gbe eto ayeye naa kale fun awon Akanda ẹda lati ọdun 1999.
- Wo ọ̀nà mẹ́wàá tí o fi lè dábò bo ara ré lásòkò ọyẹ́ yìí
- Àjọ aṣọ́bodè gbẹ́sẹ̀ lé òògùn ìbálòpọ̀ ẹ́gbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mílíọ̀nù ní ìpínlẹ̀ Katsina
- Èmi kọ́ ló gbé orin ọdún ń lọ sópin kalẹ̀, CAC ló ni í ni mó n ṣe àkójọ orin- Fasoyin
- Ṣé ẹ ti ra fìlà ọdún? Dárúkọ ọjà Kérésí kan tí ẹ̀yin ti rà
- Ibi tí o bá dágbére fún ẹbí àti ará ní kí wọ́n ti ba ọ lásìkò ọdún Kérésì yìí- Akọ́ṣẹ́mọ́ṣẹ́ Bolarinwa
- Lásìkò ìsìnmi àti pọ̀pọ̀ṣìnṣìn ọdún yìí, Òbí gbọ́dọ̀ fi àsìkò sílẹ̀ fi tọ́jú àwọn ọmọ wọn
Bakan naa ni arabinrin Favour Tioluwani lesekese naa gba awọn Obi akanda ẹda ni imọran pe pe ki wọn ma gbe iru awọn ọmọ to ni ipenija ara bẹẹ pamọ mọ.
O ni ko si ẹni ti Olorun ko le lo.
Awọn akanda ẹda, Opo ati awọn to ni ipenija ara naa ba BBC sọrọ pẹlu ọkan imoore pe ọdun yii yatọ fun awọn.