Christmas: Ṣé à ń lọ s'ílé ọ̀dún pọndandan? Ohun tó yẹ kóo mọ̀ rèé- Olatunbosun Bolarinwa
'Má lọ wọ sọọ̀lẹ̀ lásìkò ọdún yìí o! Gbọ́ àwọn ìkìlọ̀ yìí'
Ẹ gbọ́ kìí ṣe gbogbo ìrìnàjò ló pọn dandan.
Bi o ba wa pọn dandan fun ẹ paapaa lasiko ọdun yii, wo fọnran to wa ninu iroyin yii fun ẹkunrẹrẹ alaye awọn koko pataki to yẹ ki o mọ koo to gbera irinajo.
Ni kanmọ kanmọ, Ogbeni Olatunbosun Bolarinwa to jẹ onimọ nipa eto aabo nilẹ Naijiria fa awọn eeyan leti bi wọn ba ti rii pe afi dandan ki wọn rinrinajo.
- Wò ìdí tí téélọ̀ rẹ fi já ọ kulẹ̀ lásìkò ọdún Kérésìmesì
- Àwọn ènìyàn kò ní máa san owó iná mọ̀nàmọ́ná tí wọn kò lò tí mo bá di ààrẹ Nàìjíríà – Tinubu
- Ìjọba Osun gbé orúkọ àwọn tí ọkọ̀ ìjọba tí iyé rẹ̀ tó #2.9bn wà lọ́wọ́ wọn jade
- Wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré Yorùbá tó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà míì àti orílẹ̀èdè míì
- Kò sí ọdún tí ọjà ré tà tó ti Kérésì- Alhaja Shakirat
Asiko pọpọṣinṣin ọdun Keresi mu ki awọn eeyan gbagbọ pe o ma n mu ọpọ ewu dani. Nitorinaa onimọ Bolarinwa ni:
- Rin irinajo rẹ ni kiakia
- Ma rinrin oru
- Lọ wọ ọkọ ni ibudokọ, ma wọ sọọlẹ lasiko ọdun
- Wo ihuwasi dẹrẹba to n wa ọkọ rẹ.
- Kò sí arúgbó ní Kano, Bàbá 74 gbé ìyá 84 ní ìyàwó
- Wo ọmọ orílẹ̀-èdè Republic of Benin tó ń fi ẹ̀ṣà dárà lédè Yorùbá
- 'Má lọ wọ sọọ̀lẹ̀ lásìkò ọdún yìí o! Gbọ́ àwọn ìkìlọ̀ yìí'
- Ogun 2023- INEC fi orúkọ Adelanwa rọ́pò Otegbeye fẹ́gbẹ́ òṣèlú ADC
- Wo ọmọ orílẹ̀-èdè Republic of Benin tó ń fi ẹ̀ṣà dárà lédè Yorùbá
- Ó kéré tán, ogún ọkùnrin ló n bá mi sùn lójúmọ́- Adenike Olanipekun
5. Gba nọmba aladugbo rẹ ki o si fun wọn ni tirẹ.
6. Ni nọmba ọga ọlọpaa adugbo rẹ tabi nọmba ti ijọba gbe kalẹ fun eto abo ladugbo rẹ. Eyi ko nilo owo lati pe.
7. Ibi ti o dagbere ni ki o lọ...
Ẹwẹ, onimọ nipa aabo, Bolarinwa tun sọ awọn ikilọ pato fun awọn obinrin tori iṣẹda wọn.