Aduke Chanter: Láti kékeré ni Oritoke Mathew Oluwadamilola ti fẹ́ràn kíki oríkì
Omo ajanaku kii ya rara ni awọn agba n wi.
Ọmọ to ba fẹran aṣa a maa gbe ogo Obi ga ni
Oluwadamilola Oritoke Mathew gba BBC Yoruba lelejo.
O salaye bi oun ṣe nifẹ ede ati asa Yoruba bo tilẹ jẹ pe ọmọ orilẹ-ede Benin Republic ni kii ṣe ti Naijiria.
- Ètò 'Mr & Mrs kògbérégbè' tí ṣàkọ́bá fún mí gẹ́gẹ́ bí ọkọ nínú ìgbéyàwó - Mr Kogberegbe
- Ṣé lóòtọ́ ní pé ìlúmọ̀ọ́ká agbábọ́ọ̀lù ayé àtijọ́ Teslim Thunder Balogun gbá ṣọ́ọ̀tì gbígbóná fi pa "Goal keeper"?
- Ìdí tí kò fi yẹ kóò máa ra Tòmátò ẹ̀sà; wo àwọn kókó márùn-ún yìí
- Wọ́n gé gògòńgò ìyá wa lọ lẹ́yìn tí wọ́n pa a- Omo Iya Deeper Life
- Àwọn ọ̀rẹ́ mi lè fún mi ní 'One, one million' àwọn ọ̀rẹ́ ti yín ń kọ́? Kie kie ti sọ̀rọ̀sókè fún BBC Yorùbá
Aduke Chanter ni pe lati igba ewe ni oun ti maa n wo awon Ajobiewe Iṣẹ́ Oníbúrẹ́dì ní mo kọ́, ìfẹ́ àṣà Yorùbá ló sún mi dé ìdí ẹ̀ṣà pípé tí mo fi là- Ajobiewe ati Ibrahim Chatta gege bi awokose rere.
- Èdè ni ayé máa ń kọ́kọ́ gbà lọ́wọ́ ìran tó bá fẹ́ parun- Mama Oriki
- Wo àwọn sinimá mẹ́wàá tó gbé sinimá Yorùbá sáyé
- Àwọn àwòrán ìṣẹ̀lẹ̀ tó làmìlaaka láti ilẹ̀ Áfríkà l'ose tó kọjá
- Ogogo wá sí illé-ẹ̀kọ́ wa, mo kéwì fún un ló sọ mi di èèyàn ńlá lórí ayélujára - Akinwumi Akewi
- Mọ̀ sií i nípa Oba Yesufu Asanike , Olubadan tí kìí fi ọ̀rọ̀ sí abẹ́ ahọ́n sọ kódà níwájú sọ́jà
- Ǹkan kò lè dẹ̀rọ̀ ní Nàìjíríà láì ṣe pé á ní ìjọba míì nítorí Buhari ti dàgbà jù- Senato Fadahunsi
Oritoke Mathew menuba awon ipenija to n koju ati afojusun re