Adenike Adegboye: Ó bí ọmọ méjì ṣùgbọ́n ayé kò jẹ́ kí Iya Ibeji jèrè wọn nítorí pé..... Aderonke ọmọ Iya Ibeji ọmọ araye le
Awọn alagbara ti gba gbogbo ile ati nkan ti iya ibeji omo araye ni- Adenike Gboye Adekunle.
Mama mi ko ranti nkankan mọ; koda, opẹlọpẹ Olorun ati itọju- Omo Iya Ibeji.
Saaju asiko yii ni iroyin gbode kan pe ara Adenike Adegboye ti ọpọ mọ si Iya Ibeji ninu ere ọmọ araye le ko ya.
Leyin naa ni BBC Yoruba wa agba oṣere naa kan ti oun ati ọmo rẹ kan ṣoṣo to ku laye si sọrọ lori iṣẹlẹ naa.
- Iṣẹ́ 'lecturer' ló wù mí ṣùgbọ́n ìdí mọ́káníìkì tírélà ni orí gbé mi lọ- Asabi Siyanbola
- 'Òǹtàjà aṣọ ni mí tẹ́lẹ̀, ọ̀dá owó ló sọ mi di alábárù'
- "Ọ̀pọ̀ ènìyàn tó ń gbé ní Eko, Ibadan, Osogbo ló ti kú..."
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- Akure Ọ̀rẹ́ mi tímọ́tímọ́ tí a jọ ń ja ogun Biafra ní kí n yìnbọn pa òun - Gabriel Aladejebi
- A pàdánù ọmọ mẹ́ta léra wọn ṣùgbọ́n a padà bí ọmọ tó pọ̀ míràn, má ro ara rẹ̀ pin- Taiwo àti Kemi Korede
- O ní ìdí tí mo fi yan ilé Olórogún Ooni Ife dípò ilé ọlọ́kọ kan- Olori Tobi Phillips Ogunwusi
Aderonke Gboye Adekunle to jẹ ọmọ Iya Ibeji ṣalaye ipa ti ẹbi ati ara ti ko lori itọju iya oun.
O tun menuba iranlọwọ ti a\won osere bii Foluke Daramola Salako ti ṣe fun won.
Arun rọpa rọsẹ lo de ba agba oṣere ni, Adenike Adegboye ti ọpọ mọ si Iya Ibeji ọmọ araye le.
- Àwọn ẹ̀sùn ńláńlá tí wọ́n ti fi Tinubu, Atiku àti Peter Obi tó ń díje dupò ààrẹ ní Naijiria
- Kíló ń ṣẹlẹ̀ láàrin Ọ̀gá CBN Emefiele àti DSS-
- BBC n wa akọ̀ròyìn tó dántọ́ láti gba àmì ẹ̀yẹ̀ Komla Dumor
- Iyabọ Yerima, ọmọ Adisa Akinloye di adelé adájọ́ àgbà ìpínlẹ̀ Oyo
- Àdó olóró gbẹ̀mí àwọn olùjọ́sìn mẹ́wàá nínú ilé ìjọsìn
- Nítorí pé ọkọ̀ àwọn Bolanle kò ní Nọ́mbà ni a ṣe dá a dúró ṣùgbọ́n....- ọlọ́pàá