Ifayẹmi Elebuibon: Ọ̀pọ̀ òkú ló ń rìn káàkiri ìlú Èkó, Ìbàdàn, Òṣogbo
Ṣe lootọ ni akudaaya wa?
Ṣe bi eeyan ba ku nibi kan, o leepada lọ di alaaye ni ilu miran?
Igbagbọ Yoruba niyi ṣugbọn pups lo n woye pe ṣe lootọ lo wa tabi ara awọn itan atẹnudẹnu leyi.
Ninu ifọrọwerọ rẹ pẹlu BBC News Yoruba, Araba awo ti ilu Osogbo, Baba Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn ṣalaye ipilẹ ọrọ ati bi o ṣe jẹ titi kan ohun to n fa akudaaya.
Ẹwẹ, awọn ẹlẹsin tuntun bii Kiristẹni ati Islam ko fara mọ eyi. Ninu iwoye tiwọn, bi eeeyan ba ti ku, ọrun laala lati koju idajọ Ọlọrun.
Pasitọ kan naa ba BBC Yoruba sọrọ lori iha ti ẹsin Kristẹni kọ si ọrs akudaaya.
- Àrà méèrírí! Ọkùnrin tí kò ríran kan rèé tó ń lọ ẹ̀rọ ata
- ‘Ò dà bí àlá bí mọ ṣe da ìlúmọ̀ọ́ka nítorí bí a ṣe ń gbé òkú jó ní Ghana’
- Alífábẹ́ẹ́tì Ohùn Oduduwa di ìtẹ́wọ́gbà ni Ajaṣẹ
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- Dòkítà tó ṣe iṣẹ́ abẹ fún oyún inú l‘Amẹrika ló ń sọ Yorùbá yìí, bíi ẹní la oyin