Siyanbola Omolade Asabi: Hijab kò dí mi lọ́wọ́ iṣẹ́ mọkáníìkì tí mo n ṣe; ó kàn máa ń rán mi létí àwọn ǹkan ni
'Iṣẹ́ ni iṣẹ́ n jẹ́; kò sí nkan ti ọkunrin n ṣe ti obinrin kò le ṣe'
Siyanbola Omolade Asabi jẹ akẹkọo jade lati Fasiti Olabisi Onabanjo to wa ni Agọ iwoye nipinle Ogun ni iwo oorun guusu Naijiria.
Leyin to ṣetan lo ṣeṣẹ lọ kọ iṣẹ atun ọkọ ajagbe nlanla ṣe ni ipinlẹ Eko.
- Kò sí ìsinmi, ọjoojúmọ́ là ń ṣiṣẹ́ láti àárọ̀ títí di alẹ́ – Àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ọmọ-ọ̀dọ̀ ní Qatar ké gbajarè!
- Ènìyàn mẹ́jọ̀ sọ ẹ̀mí rẹ̀ nù nínú ìjàmbá ọkọ̀ ní ọdún tuntun
- Àwọn nǹkan ti yóò ṣẹlẹ̀ àti èyí tí kò níí wáyé níbi ètò ìsìnkú Pope Benedict XVI
- Wo ọ̀nà àbáyọ sí bo ṣe ń han‘run
- Olóṣèlú tó ti tán fún ni Obasanjo, kò lè gbé Peter Obi wọlé - Tinubu
Siyanbola jẹ ọmọ bibi ilu Oyo.
O ṣalaye bi irinajo aye rẹ se gbe e lọ si ibi ti ori daa si abyii.
Omolade Asabi gab awọn obinrin ẹgbe rẹ niyanju lati ma bẹru mọ.
O ni pe iṣẹ ni iṣẹ n jẹ ti eeyan ko ba ti huwa ibi lawujọ.
- Ẹni bá láyà: Ṣé ìwọ mọ àmì Yorùbá dáadàa?
- Àánú táwọn èèyàn yóò fi máa sọ wí pé ọ̀nà wo lo gbà ni yóò wọlé fún ọ ní ọdún 2023
- Ẹ máa ṣe àmín bí Adewale Alebiosu, àgbà òṣèré tíátà, ṣe ń gbàdúrà ọdún túntún fún yín
- Nǹkan ńlá tí ọkọ mi ṣe fún mi jùlọ ní ìgbéyàwó ta ṣe ní ṣọ́ọ́ṣì lẹ́yìn ọdún 21 ta ṣe ìgbéyàwó ní kóòtù - Florence Ajimobi
- Èmi kìí ṣe Ajala travel ṣùgbọ́n mo ti lọ káàkiri ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè àgbáyé, ojú mi rí tó - McDolly Ogundana