The9jaboy: Ojú burúkú ni wọ́n fi ń wo ìwé ìrìnnà aláwọ́ ewé Nàìjíríà nílẹ̀ òkèèrè- MCDolly Ogundana

Àkọlé fídíò, The9jaboy: Ojú burúkú ni wọ́n fi ń wo ìwé ìrìnnà aláwọ́ ewé Nàìjíríà nílẹ̀ òkèèrè- MCDolly

Ẹ̀yin ọmọ Nàìjíríà ẹ jẹ ki a jẹ aṣoju rere kaakirir agbaye nitori iwe irinna ọwọ wa.

Ogbeni McDolly Ogundana to jẹ arinrinajo kaakiri agbaye sọ bo ṣe bẹrẹ irinajo naa ati ibi ti ọrọ irinajo rẹ de duro kaakiri agbaye fun BBC Yoruba.

O menuba bo ṣe lọ si awọn orilẹ-ede ni North America, Africa, Asia ati bẹẹ bẹẹ lọ.

Bakan naa lo tun sọ nipa awọn ipenija to ri ati ipa to fẹ fi lelẹ lẹyin Ajala Travel to jẹ ogbontarigi arinrinajo ni Naijiria.