Bolaji Abdullahi: Mo ti ṣìnà sẹ́yìn ní mo ṣe lọ APC ṣùgbọ́n mo rí i pè wọ́n kìí ṣe ẹni gidi
Sé lootọ ni pe ibẹru Bolaji Abdullahi ni ipilẹṣẹ ọgbọn?-
Alhaji Abdulganiyu Bolaji Abdullahi to n dije dupo aṣojuṣofin agba lati ṣoju fun aarin gbungbun ipinlẹ Kwara gbalejo BBC Yoruba.
O menuba awọn iṣẹ ati eto to ni lọkan lati ṣe fun awọn eniyan ipinlẹ Kwara.
- Èmi ni mo dáńgájíá jùlọ nínú gbogbo àwọn olùdíje sípò Ààrẹ Nàìjíríà
- Baba mí fí ọwọ́ sí Folarin gẹ́gẹ́ bíi Gómìnà, ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ àwọn méjèèjì- Ọmọ Alao Akala-
- À-wọn agbégbọn jí kọmíṣọ́nà gbé lọ ní Benue wo ibi tí ìwádìí dé dúró
- CBN kéde gbèdéke 100,000 owo tí o le gbà ní ATM, POS àti bánkì lọ́sẹ̀
- Wo Billie Eilish, ọmọ ogún ọdún tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin 100 tí BBC fún ní àmi ẹ̀yẹ fún ìgbé ayé ìwúrí

Oríṣun àwòrán, @Bolaji Abdullahi
Kini Bolaji Abdullahi tun sọ?
Oludije dupo senatọ aarin gbungbun Kwara labẹ ẹgbẹ oṣelu People's Democratic Party tun ṣalaye fun BBC nipa bo ṣe rirnrin ajo lọ darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu to wa lori aleefa lasiko yii, iyẹn All Progressives Congress.
O sọ pe oun ṣina tẹlẹ ni ṣugbọn oun ti ji pada si oju ọna to dara bayii.
O sọ pe oun ko ni owo bi awọn miran ṣugbọn ni ọpọlọ lati fi di ipo naa mu.
- Ṣé lóòtọ́- Bóo bá ń mu Garri jù tí wọ́n tàn ẹ́ pé ojú dídùn ni yóò gbẹ̀yìn rẹ; gbọ́ òótọ́ lẹ́nu onímọ̀
- 'Ọkọ̀ mi máà ń tẹ̀lé mi lọ rehearsal Onílù ká tó gbéyàwó àmọ́ bí mo ṣe kó wọlé tán báyìí, ó di nǹkan míì...'
- "Ọ̀pọ̀ ń gbàdúrà kí àwọn ní HIV báyìí"
- Ọ̀rọ̀ Japa dé Ekiti; 'Iléeṣẹ́ tó ní àwọn fẹ́ ran wá lọ́wọ́ lọ ìlú Òyìnbó ti -scam' wa, àìsàn déé!
- Ìrọ̀rùn ló bá dé fún mi láti bú Àarẹ Buhari -Sisi Quadri
- Aya àti ọ̀rẹ́ kọ̀ mí sílẹ̀ lẹ́yìn ti mo pàdánù ẹ̀sẹ̀ mi ṣùgbọ́n mo kọ̀ láti ṣagbe ni mo ṣe padà síṣẹ́ wẹ́dà- Yussuf