Yollywood: Kò sí ẹni ti òbí mi kò lè sọ̀rọ̀ sí -Sisi Quadri
Sisi Quadri ni ile loun ti ba eebu bibu.
Quadri Oyebamiji ni orukọ ongbontarigi adẹrin pa oṣonu ninu sinima agbelewo Yoruba ti gbogbo eeyan mọ si Sisi Quadri.
O ṣalaye kikun nipa ara rẹ ati bo ṣe bẹrẹ ere tiata fun BBC Yoruba.
- Àwọn nǹkan méje tí Peter Obi ní òun fẹ́ ṣe tó bá di Ààrẹ nìyí
- Kí ló ń sọ ọmọ Nàìjíríà d'èrò ilẹ̀ òkèèrè tí ìjọba kò ronú sí?
- Ṣé lóòtọ́- Bóo bá ń mu Garri jù tí wọ́n tàn ẹ́ pé ojú dídùn ni yóò gbẹ̀yìn rẹ; gbọ́ òótọ́ lẹ́nu onímọ̀
- Dokita yọ góòlù àti owó ṣílè nínú obìnrin kan
- Ṣé lóòtọ́ ni ìjọba Amẹrika kọ̀ láti fún Tinubu ni Físà-
Omọ ilu Iwo olodo Ọba nipinlẹ Ọṣun yii sọrọ nipa didagba rẹ ati ipa ti awọn obi rẹ ni lori iṣẹ rẹ.
Bakan naa ni Sisi Quadri gba awọn ọdọ Naijiria ni imọran lori ọjọ iwaju wọn lati tẹpa mọ iṣẹ.
Ni afikun, Sisi Quadri dahun ibeere to n jẹ ọpọ ololufẹ rẹ lọkan lori bo ṣe maa n ṣe bi obinrin ninu sinima Yoruba.
Ẹlẹekẹ eebu alawada yii to jẹ atọkun eto to tun n ṣiṣẹ alaga iduro nibi idana igbeyawo yatọ si iṣẹ ere ṣiṣe naa ni ko si ọjọ iwaju fun ọlẹ rara.
- Àwọn ọ̀rẹ́ mi lè fún mi ní 'One, one million' àwọn ọ̀rẹ́ ti yín ń kọ́? Kie kie ti sọ̀rọ̀sókè fún BBC Yorùbá
- Ọ̀rọ̀ Japa dé Ekiti; 'Iléeṣẹ́ tó ní àwọn fẹ́ ran wá lọ́wọ́ lọ ìlú Òyìnbó ti -scam' wa, àìsàn déé!
- A ò fẹ́ Ọba tipátipá tí Gómìnà gbé lé wa lórí ní Ikirun, ìwọ̀sì ló fi wọ̀ wá! - Eesa Ikirun
- Iṣẹ́ fíìmù ló sọ mi di Babaláwo, Wòlíì Ọlọ́run ni mi - Adewale Alebiosu
- Ìdásílẹ̀ ìpínlẹ̀ Ijebu ni àwa ń fẹ́, Yorùbá Nation kò ì tíì kàn wá - Ọba Adenugba
- Njẹ́ ẹ mọ pẹ̀tẹ́ẹ̀sì àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà?