Olori Tobi Phillips Ogunwusi: Ajọṣepọ̀ èmi àti àwọn Olori Ooni Ile Ife tó kù dán mọ́ran gidi

Àkọlé fídíò, Olori Tobi Phillips Ogunwusi: Ajọṣepọ̀ èmi àti àwọn Olori Ooni Ile Ife tó kù dán mọ́ran

Bí mo ṣe pàdé Ooni Ile Ife rèé, ki n to di Olori lọọdẹ ẹni bi ọkan mi- Olori Tobi Phillips Ogunwusi.

Olori Tobi Phillips Ogunwusi, ọkan lara awọn olori ẹlẹ Ooni ti Ile Ife gbalejo BBC Yoruba.

Olori sọrọ ni kikun lori itan igbesi aye rẹ ko to di arinrinoge, aranṣọ, amunidara ati ayaworan.

Bakan naa lo mẹnuba bo ṣe pade Ojaja Keji ti ọrọ ifẹ wọn si fi wọ ti oun naa fi di olori.

O tun sọ awọn idojukọ re ati bo ṣe bori pẹlu ero rẹ lori ile olorogun.

Wo bi oriki Ooni Ile Ife , oba Adeyeye Ogunwusi se dun lenu olori Tobi Phillips Ogunwusi yii.