Akinmoorin 5 new year death: Ọkùnrin náà ní pé òun á pààyàn, ó si ṣe bẹ́ẹ̀- Ará ìlú
N kò jẹ́ kí àwọn ará ìlú lọ jà ní Jobele ti awakọ̀ náà ti wa, ṣùgbọ́n à n retí ìdájọ́ ìjọba lórí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí- Oba Akinmoorin.
Ọkọ naa lo pa eeyan marun un ti awọn mii si da lapa ati kan leṣe ti wọn farapa yanayana ni Akinmoorin ni ipinle Oyo lọjọ naa.
BBC Yoruba wa ẹbi awọn to ku kan lati mọ ohun to ṣẹlẹ ganagan.
Koda, Oba Olayemi Iyiola Solomon to jẹ Amoorin ilu akinmọọrin naa ba BBC sọrọ.
- Ghana, Morocco,fi òfin de ìrìnàjò láti China lẹ́yìn tí Covid-19 tún búyọ níbẹ̀
- Babaláwo kú sórí ìyàwó 'pásítọ̀' nílé ìturá ní Ikere-Ekiti
- Nítorí Obasanjo kò fẹ́ kí ọmọ Yorúbá mìíràn ga ju òun lọ ni kò fi ṣàtìlẹyìn fún Tinubu -YWG
- Sunday Igboho fẹ́ ṣe ìwọ́de n'Ibadan lórí ọkùnrin tó dàwátì 'sọ́wọ́ Amotekun'
- Ìgbéyàwó gbajúgbajà òṣèré tíátà, Yomi Gold tí forí sánpọ́n lẹ́yìn ọdún kan!
Kabiesi ṣalaye kikun nipa bi iṣẹlẹ naa ṣe waye ati bi oun ko ṣe faaye gba awọn ara ilu Akinmoorin lati lọ ja ni agbegbe Jobele nibi ti ọkunrin awako naa ti wa.

Ajiṣegiri Jelili , Ibrahim Babatunde ati awon o ṣoju mi koro miran tun sọ igbese ti awọn fijilante ati Amotekun gbe lori ọrọ naa ni Akinmoorin.
- Òṣèrè tíátà Muideen Oladapo gbàràdá lórí ètò 'Ṣé o láyà?'
- 'Oníṣègùn, alágbo, aláàfáà, aládurà, gbogbo èèyàn ló ń wá ra ìkòkò àmọ̀ wa'
- Nǹkan ńlá tí ọkọ mi ṣe fún mi jùlọ ní ìgbéyàwó ta ṣe ní ṣọ́ọ́ṣì lẹ́yìn ọdún 21 ta ṣe ìgbéyàwó ní kóòtù - Florence Ajimobi
- -₦900,000 ni mo fi rán ọmọ mi lọ fásitì kan ní Ghana, àṣé gbájú ẹ̀ ni-
- Alága ìdúró mú ohùn mi lọ lójú agbo tí mo tí ṣe alága ìjókòó l‘Amẹ́ríkà - Bukola Alphonso-Olanrewaju
- Iṣẹ́ 'lecturer' ló wù mí ṣùgbọ́n ìdí mọ́káníìkì tírélà ni orí gbé mi lọ- Asabi Siyanbola