Ó seése kí Boris Jhonson àti Rishi Sunak sanwó ìtanràn nítorí wọ́n tàpá sófin kónílé-ó-gbélé

Oríṣun àwòrán, @Boris Johnson
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní àwọn ti ṣetán láti fi páńpẹ́ òfin gbé Akọ̀wé àgbà orílẹ̀ èdè United Kingdom, Boris Johnson.
Wọ́n kede pe oun àti Sáńsílọ̀ Rishi Sunak tí wọn yóò sì san owó ìtanràn tí wọ́n bá jẹ̀bi lílọ síbi ayẹyẹ lásìkò tí ìjọba kéde ìgbélé nítorí covid 19.
- Àkàrà tú sépo fún ayédèrú ọ̀gágun tó fi Khaki lú jìbìtì N266.5m
- "Àwọn ọmọ ogun Russia fipá bá mi lòpọ̀, wọ́n tún pa ọkọ mi"
- Ìjà ńlá bẹ́ sílẹ̀ l‘Eko láàrin igun MC Oluomo àti ẹgbẹ́ awakọ̀ márúwá TOOAN
- Kí ló dé tí ẹnu ń kun ìgbeyàwó Funke Akindele pé ó ti dàrú? Àbọ̀ ìwádìí wa rèé
- Rògbòdìyàn ṣẹlẹ̀ n‘Ibadan, ọwọ́ tẹ jàǹdùkú nílé Olopoeyan pẹ̀lú káàdì ìdámọ̀ ẹgbẹ́ Auxillary
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ní pé Osinbajo dalẹ̀ Tinubu pẹ̀lú bó ṣe kéde láti du ipò ààrẹ?
- Ìdí tí Tinubu fi ṣèpàdé pẹ̀láwọn gómìnà APC lẹ́yìn tí Osinbajo kéde lati dupò ààrẹ
Kini ileese ọlọ́pàá so?
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní àwọn ń ṣe ìwádìí ètò ayẹyẹ méjìlá tó wáyé ní òpópónà Downing àti Whitehall léyìí tí wọ́n ní wọ́n tàpá sí òfin ìogbálé corona.
Ní báyìí wọ́n ní kò dín ní àádọ́ta ènìyàn tí yóò san owó ìtànràn nítorí wọ́n ṣe ayẹyẹ ní àwọn ilé ìjọba.
Agbẹnusọ ọlọ́pàá ní àwọn kò ì tí sọ ibi ayẹyẹ tí wọ́n lọ tí àwọn fi fẹ́ kí wọ́n san owó ìtanràn náà àti wí pé ìwádìí ṣì ń lọ lọ́wọ́ lórí ayẹyẹ náà.