Akomolede àti Asa: Mọ̀ si nípa àṣà ìsọmọlórúkọ́ nílẹ̀ Yorùbá àti ìtumọ̀ orúkọ̀ fún ìkókó
Aṣa Isọmọlorukọ nilẹ Yoruba jẹ aṣa to ti wa lati ayebaye, to si yatọ si ilana isọmọlorukọ laye ode oni.
Oniruuru awọn ohun eelo adayeba si ni wọn maa n lo lati sọ awọn ọmọ tuntun lorukọ gẹgẹ bo se ba ilana aṣa Yoruba mu.
Arabinrin Modupe aya Ajileye tile ẹkọ girama St Thomas, Oke Aro nilu Akure salaye nipa ilana eto isọmọlorukọ nilana aṣa adayeba nilẹ Yoruba.
- Báwo ní ìpàrójẹ àti ìsúnkì ṣe ń wáyé nínú èdè Yorùbá?
- Kí ni "Future tense" lédè Yorùbá?
- Ṣé lóòtọ́ ni pé iṣẹ́ Àgbẹ̀ dára ju iṣẹ̀ Olùkọ́ lọ?
- Ẹ wá dánrawò níbí pẹ̀lú Àpólà Ọ̀rọ̀ Orúkọ, "Noun Phrase"
- Ẹ̀yin tí ẹ kò gbọ́ Yorùbá, ẹ ṣúnmọ́ bí láti kọ́ lítíréṣọ̀ èdè Yorùbá lórí BBC
- Ìwà ìbàjẹ̀ bíi olé jíjà, ìjínigbé àti rìbá gbígbà ní Okediji fi ṣàpèjúwe ǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà
- Agbọ́nmágbọ́ntán, Agọ̀mágọ̀jù, mọ̀ síi nípa àwọn orúkọ Ìjàpá nínú alọ àpagbè Yorùbá
Bakan naa lo mẹnuba awọn ohun eelo ta n lo feto isọmọlorukọ nilẹ Yoruba ati itumọ ti ikọọkan wọn ni.
Ajileye tun salaye ba se n fi ọkọọkan eroja isọmọlorukọ naa se adura fun ikoko lasiko ayẹyẹ naa.
Olukọ naa tun salaye pataki eto isọmọlorukọ ati itumọ awọn orukọ ti Yoruba n sọ awọn ọmọ wọn.





