Iná PHCN tó dé lójijì ṣàkóbá ńlá ní Ibadan

Àkọlé fídíò, Iná PHCN tó dé lójijì ṣàkóbá ńlá ní Ibadan

Ẹ wo bi in a naa ṣe jo to gba ounjẹ lọwọ ọpọ ara ilu Ibadan.

Loru mọju ana ni ina ṣẹyọ ni agbegbe Oni and Son ni Ring road ni Ibadan.

Ina yii lo jo ọpọlọpọ ile iṣẹ aladani keekeeke ti wọn ti n ṣe ike ati ọra nylon Iná ńlá ṣẹ́yọ nílú Ibadan, ó sọ ọ̀pọ̀ dí onígbèsè

BBC Yoruba kan si bẹ lati wo ohun to ṣẹlẹ gangan ki a si ba wọn kẹdun.

Awọn ti ọrọ kan ṣalaye ohun to ṣẹlẹ ati awọn ohun ti wọn padanu.

Bakan naa ni wọn parowa si awọn ọmọ Naijiria lati ṣaanu wọn paapaa ijọba ipinlẹ Oyo labẹ akoso Gomina Seyi Makinde lati ran wọn lọwọ.