Shehu Sani: Ọpẹ́lọpẹ́ òògùn, kò bá yíwọ́ fún mi nígbà tí mo jẹ Àmàlà àti Fúrá papọ̀

Shehu Sani

Oríṣun àwòrán, Google

Àkọlé àwòrán, Sẹnatọ Shehu Sani ni ṣẹnetọ to ṣoju ẹkun gbungun Kaduna ni ọdun 2015 si 2019 ni abẹ ẹgbẹ oṣelu APC.
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Awọn ọmọ Naijiria ti bẹrẹ si ni fi ero wọn han lori ọrọ ti Sẹnetọ Shehu Sani sọ lori ibaṣepọ laarin awọn Yoruba ati Fulani lorilẹede Naijiria.

Shehu Sani, loju opo Twitter rẹ ni oun gbiyanju lati jẹ Amala pẹlu Fura lọna ati fi ibaṣepọ laaarin Yoruba ati Fulani han, amọ igbẹ gbuuru lo ba de.

Sani ni ọpelọpẹ oogun Flagyl to gba ohun silẹ lọwọ inu rirun ati igbẹ gbuuru.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ọrọ to sọ yii ti mu ki awọn eniyan bẹrẹ si ni fi ero wọn han, bi awọn ṣe n sọ wi pe sẹnetọ Sani n sọ wi pe ko le e si ibaṣepọ to dan mọ ran laarin awọn Yoruba ati Fulani, ni awọn kan n sọ wi pe ere lasan ni Sani n ṣe.

Ọrọ ti Shehu Sani sọ

Oríṣun àwòrán, @ShehuSani

Ọkan lara awọn to fesi loju opo Twitter rẹ sọ wi pe, owe ni ọrọ ti Sani sọ, nitori naa ki awọn Naijiria fiye si ohun to sọ wi pe, ko le e si ibasepọ laarin awọn ẹya mejeeji.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Bẹẹ ni ẹlọmiran ni o n pa owe nipa idibo sipo aarẹ ti ọdun 2023, boya Hausa ati Yoruba ni yoo gbe igba ibo lati du ipo aarẹ.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Awọn miran ni ohun ti oun sọ ni wi pe iran Yoruba ati Fulani jẹ iran to le lara wọn, nitori wọn, wọn ko le ṣe papọ.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Ẹlomiran to tun fesi ni oju opo Twitter rẹ ni ọrọ ti Shehu Sani sọ fihan pe orilẹede Naijiria ko le ṣiṣẹ papọ gẹgẹ bi ọkan ṣoṣo nitori iwa imọtara ẹni nikan awọn eniyan ati iwa ajẹbanu.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Amọ, awọn miran n beere pe ta ni Flagyl to gba Sani le lọwọ inu rirun, ṣe ẹya Igbo ni tabi iru eniyan wo ni?

Skip X post, 5
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 5

Sẹnatọ Shehu Sani ni ṣẹnetọ to ṣoju ẹkun gbungun Kaduna ni ọdun 2015 si 2019 ni abẹ ẹgbẹ oṣelu APC.