Wo ìtàn tó bí oríkì 'ìjàkadì lorò Offa', àti bí wọ́n ṣe ń jà á

Àkọlé fídíò, Wo bí oríkì ìjàkadì lorò Offa ṣe bẹ̀rẹ̀, àti bí wọ́n ṣe ń ṣe é
Wo ìtàn tó bí oríkì 'ìjàkadì lorò Offa', àti bí wọ́n ṣe ń jà á

Ninu itan Yoruba, a maa n ki oriki ilu Ọffa pe ijakadi loro Ọffa. Awọn onimọ nipa itan iṣẹdalẹ Yoruba sọ wi pe itan orisun ilu Offa lo ṣokunfa ọrọ yii ati pe titi di oni ni wọn ṣi n ṣe ajọdun ijakadi naa.

Amọṣa, ohun ti ọpọ onwoye n beere ni pe ṣe wọn ṣi n gba Kabiyesi lọffa laaye lati maa jijakadi titi di oni? Ibeere yii gan an ni BBC News rinrinajo lati fi idi rẹ mulẹ ninu iroyin yii.