Wo àjọ̀dún rúnjúpa "Crab Fair" níbi tí àwọn ọkùnrin ti máà ń ba ojú jẹ́ láti gba ife ẹ̀yẹ
Wo àjọ̀dún rúnjúpa "Crab Fair" níbi tí àwọn ọkùnrin ti máà ń ba ojú jẹ́ láti gba ife ẹ̀yẹ
Lorilẹede Gẹẹsi, ilumọọka ni idije 'Runjupa' "crab fair" ninu eyi ti awọn oludije ti maa n ba oju jẹ lati gba ife ẹyẹ ẹni ti oju rẹ banilẹru julọ.
Ilu Cumbria lorilẹede England ni ajọdun yii ti maa n waye lọdọọdun, o si ti wa fun ọpọlọpọ ọdun sẹyin.
Lasiko ajọdun naa ni wọn maa n ṣe awari ẹni to le boju jẹ julọ