Ṣé ẹ fẹ́ mọ bí èèyàn ṣe lè jáwé olùborí nínú ìdìbò Nàìjíríà? Ọ̀nà rèé
- Author, Busayo James-Olufade
- Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2
Naijiria, orilẹede ti iye eeyan to wa nibẹ pọ ju nilẹ Afirika yoo tu jade lati lọdibo yan awọn adari wọn ni ọjọ Kẹẹdọgbọn, Oṣu Keji ọdun yii. Idibo yoo jẹ ọkan lara eyi to gbona janjan ju ni iran ti a wa ninu rẹ yii.

Amọ ki ni eeyan nilo lati jawe olubori?

Akanṣe eto alaye yii ṣalaye awọn nnkan ti idibo naa ba nilẹ fun apẹrẹ oniruuru ọgbọn alumọkọrọyi lati bori, ọpọ ipenija bii aisi abo, airiṣẹ ṣe, ọrọ aje to dẹnu kọlẹ ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Bakan naa ni akanṣe eto yii yanana awọn eroja to ṣe koko lati le jawe olubori ninu eto idibo.











