Ilé iṣẹ̀ ọlọ́pàá ṣetán láti lo ọgbọ́n àtinúdá láti jẹ́ kí ètò ìdìbò 2023 kẹ́sẹjárí- Egbetokun

Ọga agba fun ile iṣe ọlọpaa to n ṣe akoso ẹkun keje (Zone 7), Kayode Egbetokun ti s#or#o lori eto idibo to n b#o.
O sọ pe ile-iṣẹ ọlọpaa yoo mu iwadii ẹsẹ kuku ni okunkundun lati ri wi pe aabo fun eto idibo gbogboogbo ọdun yii yọri ṣi rere.
Egbetokun soro yii lasiko abewo re si ile-iṣẹ olopaa ti o wa ni olu ilu Abuja.
Egbetokun ni “Aye wa fun idagbasoke ninu iṣe ọlọpa o si ro awọn akegbe rẹ lati ṣiṣe takuntakun lati ri wi pe iṣe iwadiin lata benu mu yanyan.
Bakan naa lo tun pase fun ile ise olopaa FCT lati ma yẹ awọn ọko to n rin oju popo wo finifini lati kefi awọn oni wa ibajẹ lawujọ
Egbetokun ni pelu afikun awọn ọlọpa kostabu titun ile iṣẹ ọlọpa gbọdọ ba awọn eka alaabo miiran ṣiṣẹ fun idagbasoke orile-ede yii.
Oni pẹlu ipese awọn oun amuse yaa bi ẹrọ ibanisoro ọkọ irina titun ti adari FCT ṣẹṣẹ pese fun ile-iṣẹ ọlọpa,iṣẹ awọn gbọdọ Yatọ si tatehinwa.














