Ọlọ́pàá kú sẹ́nu iṣẹ́, òkú rẹ̀ di ariwó láàrín mọ̀lẹ́bí àti iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo
Ọlọ́pàá kú sẹ́nu iṣẹ́, òkú rẹ̀ di ariwó láàrín mọ̀lẹ́bí àti iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo
Ibi iṣẹ ni ripẹtọ Yusuf Sulaiman lọ ẹnu iṣẹ ọlọpaa rẹ to fi di pe wọn gbe oku rẹ wale.
Amṣa, yatọ si pe iku rẹ dun awọn ẹbi rẹ, ohun kan ti wọn tun sọ wi pe o n k awọn lominu ni bi wọn ṣe ni okunfa iku rẹ ṣokunkun ati pe awọn to yẹ ko le ṣalaye nipa iku rẹ ko le sọ ọ ni taarata bi o ṣe kun.
Iyaafin Fọlashade Yusuf to jẹ aya oloogbe naa ṣalaye pe oloogbe naa wale nigba nigba ọdun keresi lọdun 2024, o si pada ni ọjọ kẹrindinlọgbọn oṣu kejila ọdun 2024. Wọn si j n ọsọrọ lori ẹrọ ibanisọrọ.






