African Eye: Ìwádìí BBC lórí ikú tó pa ọmọ ogun 26 ní Libya láti ipasẹ̀ Díróònù àìmọ̀dí
Losu kinni ọdun 2020, ado oloro lati oju ofurufu ba awọn asẹsẹ gba ọmọ ogun lorilẹede Libya, ti mẹrindinlọgbọn si dagbere faye loju ẹsẹ.
Gbogbo awọn ikọ to n taporogan ni Libya si lo sẹ pe awọn ko lọwọ ninu isẹlẹ naa, eyi to mu kawọn eeyan agbaye maa beere pe nibo ni ado oloro naa ti wa?
Ikọ Africa Eye, to maa n finmu finlẹ nileesẹ BBC wa bọ sigboro lati sawari ohun to fa isẹlẹ naa, ti wọn si ri pe awọn orilẹede alagbara aye ko lo baalu fi jagun mọ.
- BBC Africa Eye tú àṣírí ìfìyàjẹni àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò
- Mi ò mọ nkankan nípa ọmọ Nàìjíríà tó n fi àwọn obìnrin ṣe aṣẹ́wó ní India - Abike Dabiri
- Ìwádìí fídíò ayélujára tú àṣìrì ìpànìyàn Boko Haram
- BBC tún gbé e dé! Wọ́n tú àṣírí ìfiyàjẹni àwọn Ológun àti SARS káàkiri Nàìjíríà
- Bí ìròyìn BBC nípa oògùn ikọ́ Codeine ṣe ń tún ayé tó ti bàjẹ́ ṣe
- 'O yẹ kí ìjọba ló ìmọ̀ ẹ̀rọ ìwádìí sátáláìtì láti mú àwọn Boko Haram'
- Wọ́n ti sún ìdájọ́ àwọn sójà tó pa ìyá àti ọmọ ní ọdun 2018 sí oṣù tó m bọ̀
- Mo gba kádàrá pé mi ò lè bímọ nílùú tó jẹ́ pé ọmọ pọ̀ lára àwọn obìnrin
Ohun ti wọn n lo bayii ni baalu kekere kan ti wọn n pe ni diroonu lati maa fi ransẹ ogun sira wọn yika agbaye.
Iwadii ikọ Africa Eye, ninu fidio yii, si fidi rẹ mulẹ pe, orilẹede United Arab Emirate UAE ati Egypt si lo wa nidi aifararọ̀ ilẹ Libya, bi o tilẹ jẹ pe wọn tọwọ bọ iwe adehun fun ajọ isọkan orilẹede agbaye pe awọn yoo jẹ ki ogun simi ni Libya.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Nàíjíríà ti pín yẹlẹyẹlẹ láyé Buhari, ìjákulẹ̀ dé! - Obasanjo gbarata
- Olùkọ́ mi ń bá mi lòpọ̀ kí ń le yege ìdánwò WAEC - Akẹ́kọ̀ọ́ l‘Ogun
- Olólùfẹ PDP 18 kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ lásìkò tí wọn ń lọ pàdé gómìnà
- Iyabo Ojo ṣílé, Toyin Abraham fẹ́ ṣílé iṣẹ́ f'ọmọ, àtàwọn nǹkan míràn lágbo òṣéré
- Wo fọ́tò àrà MC Oluomo, Pasuma àtàwọn òṣèré tíátà míì níbi ìṣílé Iyabo Ojo
- Wo ìyá ọlọ́mọ mẹ́ta tó ti pé ọdún 48 tó ń ṣe ìdánwò WAEC, kó le di nọ́ọ́sí
Bakan naa ni iwadii naa ni UAE lo lo Diroonu fi yin ado oloro to pa awọn ọmọ ogun mẹrindinlogun ni Libya losu kinni ọdun 2020.