Iyabo Ojo house: Iyabo Ojo ṣílé tuntun, Eko mì tìtì

Gbajugbaja oṣere tiata Yoruba, Iyabo Ojo ṣi ile tuntun nibi ti ọpọlọpọ awọn ẹbi, ọrẹ ati ojugba rẹ ninu iṣẹ tiata peju si.

Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Inu ile ọhun ree.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Inu ile naa dun wo loju.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Iyabo Ojo ṣi ile tuntun laarin ọsẹ, nibi ti ọpọlọpọ awọn ẹbi, ọrẹ ati ojugba rẹ ninu iṣẹ tiata peju si.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Ṣaaju ni ọkan lara awọn ọmọ oṣere naa, Priscilla, ti kọkọ kede lori ayelujara pe iya oun ti di onile niluu Eko.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Oṣere naa pẹlu awọn ololufẹ rẹ bii Alhajoi Ajibola Pasuma lo peju sibẹ.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Wẹjẹwẹmu ko gbẹyin nibi ayẹyẹ iṣile naa.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Madam Saje atawọn oṣere miran ko gbẹyin nibẹ.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Gbogbo faaji ni lọjọ́ naa.
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Inu ẹni kii dun, ka pa a mọ̀ra ni ihuwasi ati irinsi Iyabo lọjọ isile
Iyabo Ojo

Oríṣun àwòrán, iyaboojofespris

Àkọlé àwòrán, Iya rẹ naa ba yọ ayọ ile tuntun.
Pasuma, MC Oluomo ati awọn eekan ilu miran

Oríṣun àwòrán, Iyabo Ojo

Àkọlé àwòrán, Pasuma, MC Oluomo ati awọn eekan ilu miran fi ijoko yẹ Iyabo Ojo si lọjọ isile rẹ