South Korea: O ṣeéṣe láti fi òkú pamọ̀ fún ọgọ́rùn ún ọdún pẹ̀lú yìnyín ìmọ̀ sáyẹ́nsì ní South Korea
Wo ọmọ tó kọ̀ láti sin òkú ìyá rẹ̀ fún ọdún mẹ́wàá àti ìdí tó fi kọ̀ bẹ́ẹ̀.
Ọpọ eeyan lo maa n wa ninu ibanujẹ ọkan nigba ti wọn ba padanu ẹbi tabi ara wọn.
Opọ igba lo maa n dabi i pe ki àwọn ẹbi naa ma lọ laelae koda ki wọn ṣaarẹ.
- Jonathan the tortoise: Wo ìjàpá tó pé ọdún 190, òun ni ẹranko tó dàgbà jùlọ láyé
- Ìdí táwọn ènìyàn South Korea ṣe ń sin èèyàn láàyè!
- 'Èèwọ̀! Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ajá mọ́'
- Ǹjẹ́ o leè fẹ́ ẹni tó bá ń jẹ ẹran ajá?
- Ganiyu fẹ́ na pápá bora lẹ́yìn tó gún ìya ìyàwó rẹ̀ lọ́bẹ pa lọ́sàán àwẹ, ọwọ́ bá tẹ̀ ẹ́
- NAFDAC: Ẹ ṣọ́ra fún ẹja aṣekúpani Puffer Fish
- Wo òtítọ́ nípa oúnjẹ Nódùùlù táwọn ọmọde máa ń jẹ
Iru eyi lo ṣẹlẹ si Jim Jung Kil ni orilẹ-ede South Korea to padanu baba ati iya rẹ laarin oṣu mẹfa si ara wọn.
Eyi lo jẹ ko pinnu lati ma sin oku iya rẹ ti arun jẹjẹrẹ pa lẹni ọgọrin ọdun.

- Njẹ́ o mọ nípa ògẹ̀dẹ̀ tuntun tó lè bọ́ ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn lágbàyé?
- Báyìí kọ́ ní wọ́n ṣe bí èmí àti aya mi ṣùgbọ́n a kọ̀ láti tọrọ bárà- Tokotayà tó ni ìpènijà oju
- Wo àwọn oríṣìí ọbẹ̀ tí o lè fi Káún sè tí wà á gbádùn ara rẹ̀ lópin ọ̀sẹ̀ yìí
- Ṣé lóòtọ́ ni abẹ́ Venus Williams ẹni ọdún 41 ṣì dí pa, tí kò tíì bá ọkùnrin kankan lájọṣepọ̀ rí?
- Àwọn nǹkan mẹ́fà tó so Ààrẹ Muhammadu Buhari pọ̀ mọ́ Ìpínlẹ̀ Kaduna
- Okòòwò márùn ún tí o lè bẹ̀rẹ̀ nínú ilé rẹ̀
Jim fi ara oku iya rẹ pamọ pẹlu imọ ijinlẹ Sayensi to n lo yinyin ati kẹmikaa lati fi ara oku pamọ fun ọpọlọpọ ọdun.
O ni oun ṣeleri fun iya oun nigba ti irora aisan jejere yii pọ pe ko lọ sinmi ṣugbọn oun pinnu lati ṣalai sin ara rẹ ni.
