Potash: Mọ̀ síi nípa àǹfàní àti àléébù káún lílò nínú oùnjẹ- Okandeji Niniola

Àkọlé fídíò, Kaun

Opọ ọbẹ ilẹ Yoruba, Hausa ati iran Igbo ni a n fi kaun se.

Bi awon kan ṣe ni pe o lewu ni awon mii ni pe Kaun n mu ọbẹ dun sii ni awọn mii ni ajẹju rẹ ko dara fun agọ ara.

Okandeji Niniola to jẹ gbajugbaja oniṣowo kaun ba BBC sọrọ lori irufẹ awọn ọbẹ ti a n fi kaun se, awọn iṣẹ mii ti wọn n fi kaun ṣe ati ilo rẹ to pó.

Bakan naa lo sọrọ nipa awọn iṣẹ mii ti wọn n fi kaun ṣe ni awujọ.

Cynthia Oyenkwere to jẹ akọṣẹmọṣẹ nipa ohun jijẹ ṣalaye nipa anfani ati aleebu ti kaun n ṣe ni agọ ara eeyan.

O menuba bi o ṣe yẹ ki eeyan maa jẹ kaun.

Akoroyin BBC, Oyeyemi Gbenga Mustapha.