Elebuibon: Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oṣù tí òjò kò rọ̀ ní orílẹ̀èdè Cuba, Ọba ilẹ̀ Yorùbá ló pàṣẹ kí ó rọ̀ tó sì rọ̀
Ilẹ Yoruba kii ṣe eyi ti a lee fọwọ rọ sẹyin nitori ẹya ti Eleduwa ṣayan ni.
Araba awo ilu Osogbo, Oloye Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn lo sọ eyi ninu ifẹrọwerọ rẹ pẹlu BBC News Yoruba.
O ni ohun to yẹ ki awọn ọmọ Yoruba o ṣe bayii, bẹrẹ latori awọn ọbalaye to jẹ olori wọn ni lati mu aṣa ati iṣe wọn lọkunkundun.
- Kílódé tí Ọọni Ife, Oba Ogunwusi kò fi gbọdọ̀ rí ọmọ rẹ̀ tuntun ti Olorì Naomi bí títí di bíi ẹ̀yìn oṣù mẹ́fà?
- Kìí ṣe gbogbo èèyàn ló lè máa jẹ irú mi- Adebola, Iya Adigun onírú ìgbàlódé fárígá
- Àwọn Olúkọ ìpínlẹ̀ Oyo fakọyọ lórí ètò Akọ́mọlédè àti Àṣà púpọ̀
- Fatai Rolling Dollar, Ọmọ ìdílé oyè tó gbé igbá orin tí Ebenezer Obey ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ rẹ̀!
- 'Bíbélì kò ní kí tọkọ taya lu ara wọn pa'
- Àwọn oúnjẹ ilẹ̀ Yorùbá ní à ń kọ nínú Akọ́mọlédè àti Àṣà lónìí
- Àwujọ ẹ rọra ṣe ìdájọ́ ẹni tó kọ ọkọ / aya sílẹ̀ nítorí pé kò wùú- Odumosu
- Mo kọ ìwà ẹlẹ́yàmẹ́yà ló jẹ́ kí ń má a kọ ọmọ Abraka, Ebonyi, Plateau àti Benue nílé ìwé mi lọ́fẹ̀ẹ́- Oba Abolarin
- Àjákálẹ̀ àrùn tuntun tí ayé ń sọtẹ́lẹ̀ nípa rẹ̀ rèé...
- Tí mo ba ti múra bí ọkùnrin fi kọrin, kò sí ọ̀dọ̀ ààrẹ́ tí mi ò lè wọ̀- Erelu, ọmọ Elemure Ogunyemi
- Kí ni "Future tense" lédè Yorùbá?
- Awakọ̀ agbókùú, ọlọ́pàá, ológun, oníròyìn ló máa ń kọ́kọ́ dìbò ní Ghana, bó ṣe ń lọ rèé

