Grammy awards 2021 - Burna Boy, Beyoncé, àti Dua Lipa, wà lára àwọn ti wọ́n fi orúkọ wọn sílẹ̀

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Wọn ti fi orukọ akọrin, ọmọ Naijiria, Burna Boy, silẹ fun ami ẹyẹ Grammy fun ọdun 2021.
Awo orin rẹ, 'Twice as Tall', ni wọn fi orukọ rẹ silẹ fun, ni iṣọri orin to dara julọ ni agbaye, Best Global Music Award.
Isọri naa wa fun awọn awo orin to ni o kere tan, ìdá mọkanlelaadọta ohùn orin igbalode.
- Ǹkan tí ó yẹ ki o mọ̀ nípa Burna Boy
- Burna Boy fẹ́ yọ̀ǹda owó tó bá pá lóde àríyá f'áwọn tó farakásá ìṣẹ̀lẹ̀ Xenophobia
- Ṣé Burna boy yóò leè dá igbó Grammy Awards lu fún Nàìjíríà lọ́dún yìí?
- Patoranking,Teni,Burna Boy: tá ní yóò gbà àmì ẹ̀yẹ̀ Headies?
- Davido fi orúkọ bàbá rẹ̀, Adedeji, sọ ọmọ tuntun tó bí
- Àrà ọ̀tọ̀ inú orin tó jáde lọ́dún 2018 ní Nàìjíríà
Burna Boy ati akọrin mẹrin miran ni wọn jọ fi orukọ wọn silẹ fun isọri yii.
FU CHRONICLES
Antibalas
TWICE AS TALL
Burna Boy
AGORA
Bebel Gilberto
LOVE LETTERS
Anoushka Shankar
AMADJAR
Tinariwen
Igba wo lo maa waye?
Ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu Kinni, ọdun 2021, ni eto ami ẹyẹ Grammy yoo waye.
Ohun si ni ikẹtalelọgọta ti yoo waye, pẹlu isọri ami ẹyẹ ọgọrin.
Ṣugbọn ko ti i si aridaju lori bi eto naa yoo ṣe lọ, tabi awọn akọrin ti yoo ṣere nibẹ, nitori aarun covid-19.
Awọn isọri to ku ni
1.Awo orin fun ọdun 2020
BLACK PARADE
Beyoncé
Beyoncé & Derek Dixie, olootu; Stuart White, omojuẹrọ/alasopọ orin; Colin Leonard, amojuẹrọ
COLORS
Black Pumas
Adrian Quesada, olootu; Adrian Quesada, amojuẹrọ/alasopọ orin; JJ Golden, amojuẹrọ
ROCKSTAR
DaBaby Featuring Roddy Ricch
SethinTheKitchen, olootu; Derek "MixedByAli" Ali, Chris Dennis & Liz Robson, amojuẹrọ/alasopọ orin; Susan Tabor, amojuẹrọ
SAY SO
Doja Cat
Tyson Trax, olootu; Clint Gibbs, amojuẹrọ/alasopọ; Mike Bozzi, amojuẹrọ
EVERYTHING I WANTED
Billie Eilish
Finneas O'Connell, olootu; Rob Kinelski & Finneas O'Connell, amojuẹrọ/alasopọ orin; John Greenham, amojuẹrọ
- Wo bí o ṣe lè ṣe eré ìdárayá tí yóò fún ọ ní adùn àti okun fún ìbálòpọ̀
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ṣàfihàn ojú àwọn afurasí tó se ẹran ara ọlọ́pàá jẹ ní Ibadan
- Mílíọ́nù mẹ́wàá Náírà ni ilé ẹjọ́ ni kí Kábíyèsí san gẹ́gẹ́ bí owó ìtaran ilẹ̀ tí ó gbà lọ́nà àìtọ́
- Omotara pàdánù isẹ́ olówó ńlá nítorí ó fi ọtí ẹlẹ́rìndòdò sódà lá ọmọ alágbe lójú
- Ilé aṣòfin orílẹ̀-èdè UK n gbèrò fífí ìyà jẹ àwọn adarí Naijiria tó lọ́wọ́ nínú rògbòdìyàn ENDSARS
- Jemila dáná sún ilé ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ àti ọ̀rẹ́bìnrin tó bá nílé
DON'T START NOW
Dua Lipa
Caroline Ailin & Ian Kirkpatrick, olootu; Josh Gudwin, Drew Jurecka & Ian Kirkpatrick, amojuẹrọ/alasopọ orin; Chris Gehringer, amojuẹsrọ
CIRCLES
Post Malone
Louis Bell, Frank Dukes & Post Malone, olootu; Louis Bell & Manny Marroquin, amojuẹrọ/alasopọ orin; Mike Bozzi, amojuẹrọ
SAVAGE
Megan Thee Stallion Featuring Beyoncé
Beyoncé & J. White Did It, olootu; Stuart White, amojuẹrọ/alasopọ orin; Colin Leonard, amojuẹrọ














