Buhari fi orukọ awọn Minisita tuntun ranṣẹ sile aṣofin

Bi àwọn eeyan kan ṣe n pariwo pe awọn ko ri orukọ awọn ti wọn n fẹ ni a rii pe orukọ awọn miran ko si nibẹ.
Solomon Dalung to jẹ minista fun ere idaraya lati ipinlẹ Plateau ko wọ inu orukọ tuntun.
Shittu Adebayọ to jẹ m,inista fun etp ibararaẹnisọrọ lati ipinlẹ Oyo naa ko ba a.
Dan Bazzau to jẹ minista to n mojuto ọrọ eto abẹlẹ naa ko ni ba Buhari ṣe ijọba tuntun.
Audu Ogbeh to jẹ minista fun eto ọgbin ati awọn miran naa ko si ninu orukọ ti wọn fi ranṣẹ.
Ibe Kachukwu ti o n mojuto ile iṣẹ epo rọbi.
Dan Ali to jẹ minista fun eto aabo.
Iroyin nipa awọn ti Buhari ti fi orukọ wọn ranṣẹ:
Mamora, Lai Mohammed, Gbemi Saraki wà lára minista Buhari tuntun.

Ile igbimọ aṣofin agba Naijiria ti kede orukọ awọn ti Aarẹ Buhari forukọ wọn ranṣẹ fun ipo Minisita lorile-ede Naijiria.
Aarẹ ile asofin Lawan Ahmed lo ka awọn orukọ naa sita lowurọ ọjọ Iṣẹgun.
Eeyan mẹtalelogoji ni wọn fi ranṣẹ.
Lowurọ ọjọru ni wọn yoo bẹrẹ ayewo fawọn minisita ti Aarẹ Buhari fi orukọ wọ́n ranṣe si ile aṣofin agba Naijiria.
Oru ana ni wọn fi orukọ ranṣẹ sile igbimọ aṣofin ki ile to kaa ni owurọ oni.
Ikede yii waye ni aadọta ọjọ lẹyin ti wọn ṣe ibura fún aarẹ Mohammadu Buhari.
Diẹ orukọ awọn to wa nibẹ ni:
Rauf Arẹgbẹṣola fun ipinlẹ Osun
Goerge Akume fun ipinlẹ Benue
Tibi Pre Sylva ipinlẹ Bayelasa
Adebayo Adeniyi fun ipinlẹ Ekiti
Babatunde Fasola fun ipinle Eko
Olorunminbe Mamora fun ipinlẹ Eko
Gbemisola Saraki fun ipinlẹ Kwara
Lai Mohammed fun ipinlẹ Kwara
Tayo Alaṣo Adura fun ipinlẹ Ondo
Sunday Dare fun ipinlẹ Oyo
Olamilekan Adegbite fun ipinlẹ Ogun.
Chris Ngige fun ipinlẹ Anambra
Awọn miran tun ni:
Chris Ngige fun ipinlẹ Anambra
Godswill Akpabio fun ipinlẹ Akwa Ibom
Rotimi Amaechi fun ipinlẹ Rivers
Festus Keyamo fun ipinlẹ Delta
Baba Shehuri fun ipinlẹ Borno
Uche Ogah
Emeka Nwajuiba
Sadiya Farouk
Hadi Sirika
Sharon Ikeazor
Akpa Udo
Dr. Ikechukwu Ogah
Mohammed Musa Bello
Sharon Ikeazor
Adamu Adamu
Ambassador Maryam Katagun
George Akume
Mustapha Baba Shehuri
Goddy Jedy Agba
Ogbonnaya Onu
Osagie Ehanire
Clement Ike
Richard Adeniyi Adebayo
Geoffrey Onyeama
Ali Isa Pantami
Emeka Nwajiuba
Suleiman Adamu
Zainab Ahmed
Muhammad Mahmood
Sabo Nanono
Major General Bashir Salihi Magashi
Abubakar Malami
Ramatu Tijjani
Mohammed H. Abdullahi
Zubair Dada
Paulen Talen
Maigarai Dingyadi
Sale Mamman
Abubakar D. Aliyu
Sadiya Umar Faruk














